Letra

Hmmmmm Ehhh ehhh ehhh There is no one like you Jehovah We worship you, we worship you Oba aseyi o wun oba ni Oba aseyi o wun oba ni Oba to le ji to le paa oo Oba aseyi o wun oba ni E ma ma bii lere oba ni E ma ma bii lere oba ni Oba to n'ole to n'oke to no'bi gbo Kabiyesi o o olola nla To ba njagun a dabi e ni ti o le gbani ye To ba ngbaani, a dabi eni ti o le jagun Oun l'olorun ti ko yipo pada Kabiyesi o o, olori aiye Iwo shaaaa l'olorun o o o Atobajaiye baba 'dumare ee Mo sunmo'ba ni won egbeje Mo jina so'ba niwon egbefa Mo teriba o o o o Ewa ri, Ewa ri, Ewa ri f'oba ajuni lo Oba aseyi o wun o oba ni Oba aseyi o wun oba ni Oba to le paa to le jii oo Oba aseyi o wun oba ni Awon science aiye yi gbiyonju titi titi titi Won wa olorun kiri won wa de'nu osupa o Won wa de'nu òrùn, won wa de'nu aféfé Won o ri iru re won wa so pe koosi Wo ni e ma si o, kosi iru olorun tiwa Ta la ba fi o we, laiye lorun kosi o Ade ori re taloba o se, irukere oye ti o mu dani talo se Kosi e e, koma si eni to le moo o Aditu, Ajulo, Ajutan, Arugbo ojo, Jojolo Baba mi orogojigo, oloruko nla oo o o o Iwo shaa l'olorun baba agba Kabiyesi ooo, olori aiye Orun o gba, o f'aiye se 'bugbe Aiye o gba o, o f'orun se 'bugbe Mi o riru e ri, l'aiye l'orun, l'aiye l'orun, l'aiye l'orun kosi Kabiyesi oooo iwo shaaaa Oba aseyi o wun o oba ni Oba aseyi o wun oba ni Oba to le paa to le jii oo Oba aseyi o wun oba ni K'awá so pé Oba to ni wakati ti mo wa Oo je k'aiye yeeye mi o ma seun Oba to ni wakati ti mo wa Oo je k'aiye yeeye mi o ma seun Oba to ni wakati ti mo wa Oo je k'aiye se shior mi o ma seun Oba to ni wakati ti mo wa Oo je k'aiye yeeye mi o ma seun
Writer(s): Timilehin Adefowora Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out