Créditos
PERFORMING ARTISTS
King Sunny Ade
Performer
COMPOSITION & LYRICS
King Sunny Ade
Songwriter
Letra
[Verse 1]
Adeniyi lo n ki yin o
[Verse 2]
A gbe tana danu, a gbe tuntun de
Eyi ga (Ah), o ga lagaju, eyi ga
A gbe tana danu, a gbe tuntun de
Eyi ga, o ga lagaju, eyi ga
[Verse 3]
Ẹ maa gbọ
Yiyẹ ni yẹ ẹyẹle, yiyẹ ni yẹ ẹyẹle o
Rirọ ni rọ adaba Iọrun
A yẹ mi kalẹ o jare nile aye mi
A yẹ mi loke okun
A yẹ mi nilẹ Naija
A yẹ mi lode agbaye ati nile ti mo n gbe
A yẹ mi loke okun
A yẹ mi nilẹ Naija
A yẹ mi lode agbaye ati nile ti mo n gbe
Ati inu ile ti mo n gbe (Ati inu ile ti mo n gbe)
Ati inu ẹbi ti mo ni
A yẹ mi loke okun
A yẹ mi nilẹ Naija
A yẹ mi lode agbaye ati nile ti mo n gbe
[Verse 4]
A gbe tana danu, a gbe tuntun de
Eyi ga, o ga lagaju, eyi ga
African beat, tutntun la gbe de
Eyi ga, o ga lagaju, eyi ga
Yiyẹ ni yẹ ẹyẹle, rirọ ni rọ adaba Iọrun
Eyi ga
Written by: King Sunny Ade

