Letra

Ruby Ruby lanshi, Slow down on aaaa... manya diet Igbe eshin ni won pe ni loud abi Ibi ti o fe gba yen, o ma ja ticket omo iya mi, To ba easy gbabi, Ta lo wa online, Saint sami-wizzy, Akanaku, Mo man wash e, Wo n lo n feel shit mi ni street, Bo n she mugbe le, Mo da lamba le, Ma wo bi won she sare mu, Nigba ti won wa ri mi pelu wizzy nkan, gbogbo wan wa manye wu, (Wo ni) lamba, Otunba lamba, (Exclusive) Black panther, Ohun wakanda, (Woni) lamba, Otunba lamba Affordable for the street, Ishe black diner, Shebi wo lofe beef, Lo gba ile si odo eran, Alaye, eja yiyan lawa n ta, Eku ni won fi damo, Igba wo lo de to blow, What's your occupation? Alaye, mo ti san owo omo onile jo, ki n to yo foundation, Omo ase ni wo n pe ni sapon, To ba de apon pon, Ma lo yo bi apon, Chache (cheche), Gbope (gbope), Rata (rata), Japa (japa), Akanaku, Mo man wash e, Won lo n feel shit mi ni street, Bo n she mugbe le, Mo da lamba le, Ma wo bi won she sare mu, Nigba ti won wa ri mi pelu wizzy nkan, Gbogbo won wa manye wu, (Woni) lamba, Otunba lamba, (Exclusive) Black panther, Ohun wakanda, (Woni) lamba, Otunba lamba, Affordable for the street, Ishe black diner, Odieshi, Awon ota esu, Won ti bo si ori third mainland brigde, Won jo shibisi, Tecno-banter sandayi, What is slimcase? Only you, O fe gbe e mo ra?, Shenk e, Ti n ba je mourinho, o ma bench e, Sho fe dance ni? Otunba lamba, sho le last mi? At all at all ni won pe wunre, Oga ade ki o to lo, o ma mu nkan le o, Akanaku, Mo man wash e, Won lo n feel shit mi ni street, Bo n she mugbe le, Mo da lamba le, Ma wo bi won she sare mu, Nigba ti won wa ri mi pelu wizzy nkan, Gbogbo won wa manye wu, (Woni) lamba, Otunba lamba, (Exclusive) Black panther, Ohun wakanda, (Woni) lamba, Otunba lamba, Affordable for the street, Ishe black diner, Oti ye e, Ohun ye niyen, Ah, wash Oti ye, Alaye VIP lo wa, Oti ye, Gbogbo Oju e to n le yen, Ija lo ba n be, Oju e to n le yen, Eh, Oju to n le yen, Ija lo ba n be, Bouncers pe 30, Won ma ti e bole, Oti ye, Ti o ba ti mo pe o lowo VIP ko fi aye le, Bamba, Tiz slimcase in the building,
Writer(s): Ayodeji Olatunde Olowu, Oladapo Oluwafemi Oko-eko Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out