Letra

Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo n kede ogo Re Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo n kede ogo Re Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e Didara orun, o n so togo Re o Olorun Ewa Re to yi aye ka, n so togo Re o bo ti po to Gbogbo eda, eranko at'ewebe n yin O o Ise owo Re gbogbo loke nile, won n yin O o Baba Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kaja orun Ipa ese Re, o n han l'ori apata Esin Re n fogo yan, l'ori awon okun o Olola nla Kini yo waa se mi, ti n o j'okele yo, ti n o ni le juba Re Oba Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e Gbogbo eemi inu mi, o n yin O yato o, Olorun mi Iwo to mu mi la ina koja, to fi mumi goke, kini mba fi fun O Kini mo to si ninu oore ofe ti mo ri gba lodo Re O ba aye mi da majemu lati 'nu ole Oro Re ye, o si se Oba ti ki i dale oro Re Iwariri ni n o ma fi juba Re o Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re Kini yo waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out