Créditos

PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Performer
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Vocals
Babatope Joseph Temidayo
Babatope Joseph Temidayo
Drums
COMPOSITION & LYRICS
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Songwriter
Babatope Joseph Temidayo
Babatope Joseph Temidayo
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Executive Producer
Babatope Joseph Temidayo
Babatope Joseph Temidayo
Producer
Prince Oladeji Sunday Adele
Prince Oladeji Sunday Adele
Mixing Engineer
Iredumare Opeyemi
Iredumare Opeyemi
Executive Producer

Letra

Mo dúpẹ́ Ọlọ́hun o
Bàbá mi l’aládé àlàáfíà
Òun ni kìnnìún Judah
Ọ̀rọ̀ mi Àyìndé Wasiu
Ìtàn ìgbésí ayé mi
Ọmọ Síkírù méjì
Ìkan ‘déyímiká Barrister
Tó gbé Fújì fún mi
Ni mo ṣe ń jó mo ṣe ń yọ̀
Aládé àlàáfíà SK Adétọ̀nà
Bàbá mi ló ró mi láṣọ
Wọ́n ní kí Àyìndé gba double
Ọ̀túnba fìdípọ̀tẹ̀ mọ́lẹ̀ àti olórí ọmọ Ọba níjẹ̀bú
Ah! Ṣé ẹ rí ilé ayé mi
Ẹ wo ohun ti bàbá ṣe ò fún adé orí ọ̀kín
Ìsẹ̀nyí ninú mi dùn Olúayé Fújì
Ọlọ́hun Ọba ló bá mi ṣé
Ẹ lu àlùjó gbẹ́sẹ̀
Mo ní ẹ lu àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀ sókè
Ẹ lu àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Ah ah Àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀ sókè
2025 tí wọ́n ń sọ o
Olókun ń gbọ́, ọlọ́ṣà ń gbọ́
Ọdún tá a wí ti dé
2025 tí wọ́n ń sọ
Gbogbo ọmọ ṣiṣẹ́ ṣiṣẹ́ àpamọ́wọ́ owó wa
Bí ẹ bá rán owó kékeré níṣẹ́ ńlá ni yó padà
Gbogbo ọmọ ṣiṣẹ́ ṣiṣẹ́
Nínú ọdún yìí ratio one to three àní àpamọ́wọ́ owó wa ò
Gbogbo ẹni tó ń wojú Olúwa
Ó ma rí àánú gbà
Á dẹ̀ báwa d’ọjọ́ alẹ́ bó w’ọlá Ọlọ́hun o
Torí ọdún owó ti dé 2025 tí wọ́n ń sọ
Ẹ lu àlùjó gbẹ́sẹ̀
Ẹ lu àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀ sókè
Ẹ lu àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Ah ah àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀
Gbẹ́sẹ̀ sókè
Àlùjó gbẹ́sẹ̀
(Ẹ ganu sí Fújì mi)
Written by: Babatope Joseph Temidayo, Olasunkanmi Ayinde Marshal
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...