Слова

Iji ra ale, aleka malaika (aleka malaika) Ijimi ma serifu malaika mi Qdot lórúko mí Bàbá lókè má fí mí sí one corner Àgbà dé kàn tó gb'ohùn Rolling Dollar Má ṣe mí l'Aboki oníṣẹ́ Bàbá, dàkún, ṣé mí lọmọ aláṣelà Ṣébí, alapata lo lọ'run ẹran Má sọ pé ó dán ìgbàgbọ' mí wo K'ayé má bá tú mí l'aṣọ wo Ọmọ Adeboye ó gbọ'dọ' wọ ẹkùn ègùn Ọmọ alapata ó gbọ'dọ' jẹ egungun Ṣé mí ní dá rocha, má ṣe mí l'alakisa Ọlọrun àwọn Ọlọrun Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani (mo gbé oh) Mó tí fití Késárì fún Késárì (fún Késárì) Mó tí lo church, mó tí lọ mosa'asi Àgbàlagbà mo' mí dáa lọ yí Ẹlẹdà má sún (ẹlẹda mí má sún) Ẹlẹda má sún (ẹlẹda má sún) Ẹlẹda mí má sún (woah) Mó gbàgbọ' pé ọmọ Ọlọrun ní Jésù Mó gbàgbọ' pé òjíṣẹ́ rẹ l'Anọbi (sallallahu 'alayhi wa sallam) Ọlọrun ó ṣebì èèyàn lo ń ṣe'ka T'ayé bà bínú wọn má ní kí Eyimba na Barça pàá oh Qudus ó mọ pé ogún láyé oh Ń bá rà ìbọn, ń bá rà 'dá Àwọn tẹ gbà'yé fún, kó ṣ'ojú àyé K'oma f'áyé mí t'afala Àdàbà tí ko lé fo mọ, oh-ohh Ọmọ aráyé lo tún dáa Mó tí gbé Bíbélì, gbé Qurani Mó tí fití Késárì fún Késárì Mó tí lo church, mó tí lọ mosa'asi Àgbàlagbà mo' mí dáa lọ yí Ẹlẹda má sún (ara eli Mikail) Ẹlẹda má sún (ara 'ba malaika fali mi) Ẹlẹda mí má sún (e li kulu modá bara n kadu 'lifa) Ẹlẹda má sún (ẹrí ń bẹ lókè Agelu) Ẹlẹda mí má sún (sata ta ulehu) Ẹlẹda má sún (orí mí jọọ-) Mà jẹ ń d'àgbàya kín tó d'olówó oh-oh Ẹ'dá mí jọọ (orí mí jọọ oh) Alola fari gi noti, seri moda fa'yallahu (fa'yallahu) Bàbá dá mí lóhùn (dá mí lóhùn) Àgbà dé eee (àgbà dée) Àgbà dé kàn tó gb'ohùn Rolling Dollar (Yeah, ayy-ayy-ayy) (Bàbá dá mí lóhùn) Fali uli faki ilaina (ẹlẹda má sún) (Yeah, who's here?)
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out