Видео

AWADE - K1 DE ULTIMATE
Смотреть видео на песню «{artistName} — {trackName}»

Создатели

ИСПОЛНИТЕЛИ
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Исполнитель
МУЗЫКА И СЛОВА
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Композитор
ПРОДЮСЕРЫ И ЗВУКОРЕЖИССЕРЫ
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Продюсер
Segun Michael Ajayi
Segun Michael Ajayi
Продюсер

Слова

K1 de ultimate Fuji the sound Olorun lo fi ran emi Ayinde o God sent Iya ati baba won bi mi da Emi gangan mo tun tun ara bi Loruko oun se n ga si Iya ati baba won bi mi da Emi gangan mo tun tun ara bi Loruko oun se n ga si Omo gidi sa lo ye ka ya Ka si tun je ari koserere Ni tori awon ewe ni ojo iwaju Boy se rere boy o se re oooo Ba siko ba to Oluaye fuji mi Boy a ma ba aye ti e lo Ere sun si waju ko ti igba kankan duro o Eyan to ba ba oko yi daju la o jo Gun le si ebute ayo o Emi lo ni fujimi Tori onilu oni fe o tu Igba kan lo igba kan bo Ojo n gun ori ojo Gbogbo igba ki gba to ba de Layi eledumare je ko ba wa lara mu Eku ati ijo Se daada ni Eku ati ijo Laada ni Se alafia le Wa Gbogbo ile nko o Eku ati ijo E daada ni Eku ati ijo Daada ni Se alafía le wa T'aya tomo nko o Lse to se omo fun ogun odun Ya to je omo fun osu mefa o Bi o ba pa omo A si leyin omo ni Me le ni kan se o Me le ni kan se o Me le nikan se ile aye o0o Me le ni Kan se ile aye Ta da dan ta da Pa ra ra pam pam Pam pa ra Ton ton ton ton To to Me le ni kan se ile aye No one than God There is a moment in ones life time You've got to make an impression right on time Behold I have set the land before you go in And possess the land which the lord swear unto your fathers Abraham, Issac and Jacob To give unto them and to their seed after them The Lord your God hath multiplied you And behold Ye are this day as the stars of heaven For multitude Deuteronomy chapter 1 verse 1 to 10 Awade n dededede de Awade Awa la n ko omo lede awade Awade n dededede de Awade Ayinde la n ko omo lede awade Omo eni o se idi bebere Akanke ade mi Melissa Ka fi ileke si idi omo elo mi Ayinde wasiu teni n teni teni n teni Ba n da kasa fomo Anifowose Na ehn Ban da kasa fomo Anifowose Ehn a enn Ban da kasa kasa kasa kasa kasa fomo Anifowose Ehn a ehn Me le sa yi jo fuji Tori alujo nbe ni be (Me le sa i jo Fuji) Me le sa yi jo fuji o Me le sa yi jo fuji o Tori alujo po pupo ni be Me le sayi jo Fuji
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out