album cover
album cover
Yeyeye was released on July 18, 2016 by Eniobanke as a part of the album Iwa
AlbumIwa
July 18, 2016
LabelEniobanke
BPM68
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Lyrics

A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Ọ'dọ'mọdé wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Àwọn àgbàlagbà wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'ogbó o, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Ọmọdé yìí onínú-ire
Bo jáde ní'lé, ibi ò ní kàn ọ' o
Bo bẹ'rẹ' l'óko, o ò ní d'àwátì
Ìbàlẹ' ọkàn ni t'aṣòótọ' o
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Bá a bá ṣe rere, à pẹ' bí ọ'pẹ (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Bí igi ìrókò tí nbo'lé b'àlejò (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'ogbó o
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ì gbọ' 'kú ọkọ', a ì gbọ' 'kú àdá o
A ti já'wé gbígbó ká a má nù l'éwe
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Ọ'dọ'mọdé wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Àwọn àgbàlagbà wọn ìí gbọ' 'kú aṣọ o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'ogbó oo
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o, (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ò ní d'àgbà òṣì a tọrọ jẹ (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ò ní d'àgbà ọ'dẹ' à mú ṣe yẹ'yẹ' o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ò ní d'àgbà-yà ọ'dagború (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
A ó d'ogbó o
A ó d'àgbà, a ó pẹ' n'ílẹ' yìí o (yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
(Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó)
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Yẹyẹyẹẹ' l'aṣọ gbó
Written by: Olusegun Akinsete Akinlolu
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...