Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Tim Godfrey
Tim Godfrey
Performer
Xtreme
Xtreme
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Tim Godfrey
Tim Godfrey
Songwriter
Xtreme
Xtreme
Songwriter

Lyrics

ORIKI : Ka-biyesi atoperi Eledumare mi se Ka-biyesi agba nla atoperi Eledumare mi se Baba mi awimayehun, Baba mi awilese Baba mi aselewi, Baba mi, Baba nla ti ngbani Gbani Gbani lojo isoro, eleti gbohun gbaroye Afetilukara bi ajere, eru jeje leti okun pupa Oba to tele bi eni nteni, Ota somo bi eni taso Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai : Eyin loba to nse oun gbogbo lodu Eyin lakoda, eyin laseda, eyin laweda Eyin lameda, ogbagba tirin gbagba Alagbada ina, alawotele oorun Alade gbedegbede bi eni n layin Edumare moti mope mi wa feni tope ye fun Moti fiyin feni tiyin se tire o Eni to n se mimo, to n je mimo, to n mu mimo To n gbe bi mimo, to niwa mimo, Alade ogo Talaba fi o we, na you bi ano, na you bi oni Na u tuni lola, ope ye o o Baba, Edumare gbope wa Tire ni o, tire ni o Mo fi sile fun o Females: Owuro mi, osan mi, ale mi o o Tire ni Oluwa (Modulation) Tire ni o/7x (Modulation) Tire ni o/7x (Modulation) Call- my praise Resp: my praise Call- Belongs to you Resp: Belongs to you Call: Ese Resp: Ese Call: Adupe o Resp: Adupe o Call: Igwe/6x (nna naba me) Resp: Igwe
Writer(s): Timothy Godfrey, Emmanuel Samuel Giveson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out