Credits

PERFORMING ARTISTS
Ajebutter22
Ajebutter22
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Akitoye Balogun
Akitoye Balogun
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Doc Def
Doc Def
Producer

Lyrics

(I love you)
I love you
(I, I, I, I love)
(I love you)
For the music, yeah
(I, I, I, I love)
There, there for the beat, for the beat, for the beat
Ajebutter lọmọ, swagu
(I, I, I, I love)
Swagu, swagu, swagu
Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu
Team swagu
Swagu, swagu, swagu
Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
Swagu, swagu
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
No more Versace
That's too mystery
That's not my (Swagu)
Ọtẹ guys
Ama nà ọtẹ guys to the full men
(Swagu)
So many guys don dey copy my style
So I had to change up my (Swagu)
Gbogbo àwọn guys tàn like mi tẹlẹ
Àwọn nàà fẹ join team (Swagu)
Ìdí yẹn bí Nicki Minaj
Like I leave us, good to be mo kàn ṣe discharge
Like Alimo credit bí mo wá lọ recharge
Ajebo bad gàn, show her who is in charge, ah
Ọmọ school tàn n sùn pẹlú teacher
Half parting mi n ṣe politician
Bad current mi n ṣe electrician
Because they feel my swagu
Swagu, swagu, swagu
Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu
Team swagu
Swagu, swagu, swagu
Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
Swagu, swagu
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
Swagu, swagu
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
Butter, this is my time
If I don't blow then it may never happpen for me
Ìdí yẹn slapping for me
My song in your car and your girl started asking for me
Everything not as it seem
Some of my guys t'ájọ ṣe genesis
Ìkan ninu wọn wà tí dí nemesis
It may never cease
But, átí wọ inú club, wọn má pop off
And if I see your girl, no rock off
Àwọn frosh, àwọn balu
Lé wọn kúro lọ̀nà f'àwọn
Átí wọ inú club, wọn má pop off
And if I see your girl, no rock off
Àwọn frosh, àwọn balu
Jẹ k'ọn kúro lọ̀nà fún àwọn ti swagu
Swagu, swagu, swagu
Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu
Team swagu
Swagu, swagu, swagu
Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
Swagu, swagu
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
Swagu, swagu
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
Shout out to all of Ìsàlẹ̀ eko
'Cause àwọn tèmi níyẹn
And to my guys out in London
Àwọn tèmi níyẹn
We move
I tell my whole squad, we move, we move
We move
When I say squad, we move, we move
(Swagu, swagu)
We move
I tell my whole squad, we move, we move
(Swagu)
We move
When I say squad, we move, we move
(Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu)
Ajebutter bad boy
Tell my whole squad we move
Ajebutter bad boy
Tell my whole squad we move
(Ẹ kúrò lọ̀nà f'àwọn goons mi, swagu)
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
(Swagu, swagu)
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
Wọn dáràn, Ìgò lojú àwọn ọdáràn
(Swagu, swagu)
Ọlọ́run, lọ́run, lọ́run, lọ́run
(love you)
(I, I, I, I love)
(I love you)
(I, I, I, I love)
Written by: Akitoye Balogun
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...