Lyrics

Gbogbo awon ayanfe e lo se logo Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo Oluwa lo pe mi lo yan mi wa se, gbogbo awon ayanfe e lo se logo Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo Kita kita ko ran, giri giri ko ran o Kita kita o ran o, giri giri ko ran o Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye Ori mi maa je n si won w'aye l'aye lasan lasan Eda mi ma je n se akobata fun egbe mi Tori kita kita o ran o, giri giri ko ran o Kita kita o ran la, giri giri o ran o Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye Emi ti gbo ohun Oluwa ti o wipe Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin Aye le ma sata Aba, Let them say
Writer(s): King Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out