Lyrics

Mo de o baba, mo wa ṣọpẹ, ore nla Baba ti gba Awọn ọmọ rẹ lo timi ninu E ba mi dupẹ f'oluwa to ran mi lọwọ Baba gba mi lọwọ ìṣòro Ka to ni jẹ Emi mo fi fún oluwa Fún ọrẹ rẹ Ọpẹ mi pẹlẹ si mi o tumi ninu Mo ti dá majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a Mo wa ba olore ọfẹ To ṣe ye bi, to muṣẹ wa Mo de o baba, mo wa ṣọpẹ, ore nla Baba ti gba Awọn ọmọ rẹ lo timi ninu E ba mi dupẹ f'oluwa to ran mi lọwọ Baba gba mi lọwọ ìṣòro Ka to ni jẹ Emi mo fi fún oluwa Fún ọrẹ rẹ Ọpẹ mi pẹlẹ si mi o tumi ninu 'Tori, mo ti dá majẹmu o e, mo ti dá majẹmu o a Mo wa ba olore ọfẹ To ṣe ye bi, to muṣẹ wa Ore ọfẹ lo damisi, mo ma yẹn náà Ọlọlá lo ji ọta mi o Emi a jo Iku folọ amuse gbé o eyitope Baba wa leti ọdọ mi to n wo mi lọwọ Ẹ ba mi jo ẹyin ara mi Ile ayé, k' ọpẹ mi, kòtò ọwọ' laan tọrọ Mo ti dá majẹmu o e, mo n san majẹmu mi o a Mo wa ba olore ọfẹ To ṣe ye bi, to muṣẹ wa
Writer(s): Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out