Lyrics

Baba wa ti n be l'orun Owo ni f'ooko Re Ife Tire ni ko se Lori oro aye wa Baba wa ti n be l'orun Owo ni f'ooko Re Ko s'ohun to le F'Olohun lati se Ko s'ohun to le F'Olohun lati se O lana s'okun Jabesi d'oloriire Igba lo yato Ko s'ohun to le F'Olohun lati se Ko si o... Ko s'ohun to le (Omo ma gbagbe, ko s'ohun to le) F'Olohun lati se (Iri a dojo, ojo a ro, ile a gba imisi) Ko s'ohun to le (Ibukun a wa, ma gbagbe o) F'Olohun lati se O lana s'okun (Okun di 'yangbe ile, ohun ta a ro pe o le sele) Jabesi d'oloriire Igba lo yato (Omo) Ko s'ohun to le (Ko si, ko si, omo ma gbagbe o) F'Olohun lati se Igbagbo la nilo fun 'se iyanu Re (Baba Nla) Ireti la nilo fun 'se iyanu Re (Baba Iyanu) Ife la nilo fun 'se iyanu Re (Ko le se) Ko s'ohun to le F'Olohun lati se Igbagbo la nilo fun 'se iyanu Re (Baba Nla) Ireti la nilo fun 'se iyanu Re (Baba Iyanu) Ife la nilo fun 'se iyanu Re (Ko le se) Ko s'ohun to le (Omo ma gbagbe, omo ma gbagbe o) F'Olohun lati se (Igbagbo to duro giri) Igbagbo la nilo fun 'se iyanu Re (Baba Nla) Ireti la nilo fun 'se iyanu Re (Baba Iyanu) Ife la nilo fun 'se iyanu Re (Ko le se) Ko s'ohun to le (Omo ma gbagbe o, omo ma gbagbe o) F'Olohun lati se Ko s'ohun to le (Se o gbagbe se, opo la ri ka) F'Olohun lati se (Opo ni o tie l'akoole, opo la n ri...) Ko s'ohun to le (sugbon ta o k'obi ara si...) F'Olohun lati se (Ko si, ko si ooo) O lana s'okun (Nigba t'aye ro p'o tan, nigba t'aye ro p'o tan o) Jabesi d'oloriire (Emi naa mo ni ijerisi temi) Igba lo yato (Ko si, ko si o) Ko s'ohun to le (Omo ma gbagbe) F'Olohun lati se Baba wa ti n be l'orun Owo ni f'ooko Re (Oni iyonu julo, Baba) Ife Tire ni ko se Lori oro aye wa Baba wa ti n be l'orun (Alagbara julo) Owo ni f'ooko Re Bi mo ba f'oju okan wo okun to pinya, eru a ba mi o Ara mi a segiri wipe Alagbara ni Baba wa Igba lo yato, omo eniyan, o je lo gbe je Tete ko se temi lo n beere, A a se 'yanu Bi mo ba f'oju okan wo okun to pinya, eru a ba mi o Ara mi a segiri wipe Alagbara ni Baba wa Igba lo yato, omo eniyan, o je lo gbe je (Ma gbagbe o, ma gbagbe o) Tete ko se temi lo n beere, A a se 'yanu A a se 'yanu A a se 'yanu o, A a se 'yanu A a se 'yanu Ni se lo kan dabi pe o le gan O dabi pe o le Oniyonu ni Baba wa A a mu aanu wa A a se 'yanu, omo ma gbagbe A a se 'yanu Tete ko se temi lo n beere o A a se 'yanu (Ko s'ohun ti o le se, awa ni k'a t'ero ara wa pa, k'a ye 'ra wa wo, k'a bo sinu ife Oluwa gangan) A a se 'yanu (Eni ikosile wa, nise lo kan dabi pe o le gan, A a se 'yanu o) A a se 'yanu Tete ko se temi lo n beere o A a se 'yanu Oluwa mo gba o gbo Ko sohun t'o o le se Mo gbagbo pe iyanu a sele K'o ri fun mi gege bi oro Re Emi yoo sa ma se ife Re Oluwa, k'o ri fun mi gege bi oro Re Amin k
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out