Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Elijah Daniel Omo Majemu
Elijah Daniel Omo Majemu
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Elijah Daniel Omo Majemu
Elijah Daniel Omo Majemu
Songwriter

Lyrics

Owo to so ile aye ro Ti enikeni ko le so nipa re Eri to gbe aye duro t'enikeni ko le je afi ohun nikan soso Bi aye mu ni ile aye yi bo se wuwo to Te fi ara owo yin fi omi lasan di mu ni awosanma Bawo ni agbara yin ti po to Opo to di aye yi mu Opo to so aye ro Opo to so aye mi ro Opo ti o je n jabo Opo to so aye mi ro Opo ti o je n jabo Igi l'eyin ogba mi E ma se o Baba Igi l'eyin ogba mi E ma se o Baba Opo to so aye mi ro Opo ti o je n jabo Opo to so aye mi ro Opo ti o je n jabo Igi l'eyin ogba mi E ma se o Baba Igi l'eyin ogba mi E ma se o Baba Opo to so aye mi ro Omi l'eyin eja mi Apata ti mo duro le Agbelebu ti o je n subu Igi l'eyin ogba mi E ma se o Baba Igi l'eyin ogba mi E ma se o Baba Won o ba ti gbagbe mi s'abule Aanu re lo mu mi ja gbangba Won o ba ti ta mi s'oko eru Aanu re lo mu mi ja gbangba Alatileyin mi E ma se o Mo dupe oore Igi l'eyin ogba mi To duro gboin e ma se o Ero ota ni ka lo s'ajo Ife inu won ni ka ma pada wale Wo bo se mu bori ogun Awon ota mi n re le Agbara re Agbara re Agbara re lo n gbe mi leke Mo ma dupe o Mo yin o logo Opo to so aye mi ro (Opo to so ye mi ro) Opo ti o je n jabo (Erin lakatabu okunrin ogun) Opo to so aye mi ro (Ato farati ma ye) Opo ti o je n jabo (Iwo lopo ti o je kin jabo) Igi leyin ogba mi (Igi leyin ogba mi) E ma se o Baba (E ma se o Baba) Igi leyin ogba mi (Igi leyin ogba mi) E ma se o Baba (Kabio osi atoperi Eledumare) Igi leyin ogba mi (Erin lakatabu okunrin ogun) E ma se o Oloore (Jagunjagun ti o fi tibon se) Igi leyin ogba mi E ma se o Baba
Writer(s): Elijah Daniel Omo Majemu Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out