Music Video

promo ojo ale by Friday paul
Watch {trackName} music video by {artistName}

Credits

COMPOSITION & LYRICS
Evang paul friday omo abule
Evang paul friday omo abule
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
T-Reign
T-Reign
Producer

Lyrics

Eru ojo ale n ba mi Tori n mo bi yoo ti ri Eru ojo ale n ba mi o o Tori n mo ibi oloko N wa mi lo O n ba mi o Eru ojo ale n ba mi Tori n mo bi yoo ti ri Eru ojo ale n ba mi oo Tori n mo bi oloko N wa mi lo Opo arugbo ni mo ri Lojo ale ti won fo loju o To n mu won rin kiri Ko ma ki se pe Won ko le gbadura Ibi tile su bawon Sowun lo wa yen Opo arugbo ni mo ri lojo ale Tiwon toro je ti won n mu won To kiri ki ma i se pe won ko Lolorun o ibi tile su ba won So hun lo wa yen Eru ojo ale n ba mi Tori n mo bi yoo ti ri Eru ojo ale n ba mi o o Tori n mo ibi oloko N wa mi lo O n ba mi o Eru ojo ale n ba mi Tori n mo bi yoo ti ri Eru ojo ale n ba mi oo Tori n mo bi oloko N wa mi lo Opo arugbo ni mori Lojo ale ti won ti sise Latowuro won Sugbon ti won o ri ohun Kojo o Ki ma i se pe o Tori won yole Opo arugbo ni mo ri lojo ale Ti won n jeya bi enipe Won o bimo saye Ko ma i se pe nitori Won o bimo o Sugbon aye lo ko Lo ko eyin omo si won Opo sise sise bi alai se Ko ma si n ti won le toka si Ko ma i se pe won yole o Ibi tile su bawon Sohun lo wa yen Eru ojo ale n ba mi Tori n mo bi yoo ti ri Eru ojo ale n ba mi o o Tori n mo ibi oloko N wa mi lo O n ba mi o Eru ojo ale n ba mi Tori n mo bi yoo ti ri Eru ojo ale n ba mi oo Tori n mo bi oloko N wa mi lo Won ni o ye sebi O lo ni gbo Won o ye seka O lo ni gba o Ojo aye re n yo lo Bi abela o je ronu aye re Ki wo tete se rere E o wo oju ojo Se wo o wo oju agogo E o wo ohun ago wi Se wo o wo oju ago ni Igba eda n re bi ano Ojo oni n ba ti e lo Ohun iseju kan baje Ogun odun le ma tun se Agbere lo se titi to sogo nu Oti lo mu titi ojo aye re lo Agogo to ka wakati o duro o Ronu re wo ko ma bola re je Ika lo se to fi pa omo inu re tan Sika sika yin o wa fi kan sera re Gbogbo omo to bi o ri pe Won o ni laari Ronu e wo nitori ojo ola E o wo oju ojo Se wo o wo oju agogo E o wo ohun ago wi Se wo o wo oju ago ni Igba eda n re bi ano Ojo oni n ba ti e lo Ohun iseju kan baje Ogun odun le ma tun se Kojo ola mi le dara o Mo to o wa olorun Ba mi tunse Kojo ola mi le dara o Mo to o wa olorun Ba mi tunse Mi o lebu ajitola Mi logun ajisa Mo to o wa olorun o Ba mi tunse Ki n le lojo ale baba Ki n ma ba rare o jare Mo to o wa olorun Ba mi tunse Mo to o wa o Mo to o wa olorun Ba mi tunse
Writer(s): Evang Friday Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out