album cover
Ojonlo
2
World
Ojonlo was released on August 8, 2021 by Kafayat Quadri as a part of the album Humanity
album cover
Release DateAugust 8, 2021
LabelKafayat Quadri
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM89

Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Kafayat Quadri
Kafayat Quadri
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Kafayat Quadri
Kafayat Quadri
Composer

Lyrics

Ojonlo ojonbo ife (ife)
Asiko nlo asiko nbo
Fe ‘mi ati ire
Kini mo ri loju re
Kini mo gbo lenu re, ife
Ewe to jabo lori Ini
Oluwa nikan lomo, ife
Bi okan mi seri iiii
Oluwa nikan lomo
Bi okan re se ri iiii
Ma se beru lati fi han mi
Ojonlo ojonbo ife (ife)
Asiko nlo asiko nbo
Fe ‘mi ati ire
Ojonlo ojonbo ife (ife)
Asiko nlo asiko nbo
Fe ‘mi ati ire
Gbogbo nkan ton lo laye yi
Koseni tomo
Sugbon nigba ti oju mi
Pade tire
Itunmo de ona la
Ogbon be lori re
Iwa tutu iwa to daa
Lo fi rewa
Ojonlo ojonbo ife (ife)
Asiko nlo asiko nbo
Fe ‘mi ati ire
Ojonlo ojonbo ife (ife)
Asiko nlo asiko nbo
Fe ‘mi ati ire
Ma se gbagbe mi
Enu kin gbagbe ofun
Fi ife pade mi
Fi erin pade mi
Ma se gbagbe mi (Oh oh oh)
(Uhuhuhuuuhuhuhuhuuu)
Fi erin pade mi (Oh oh uh uh)
Fi erin fi ife
Fi erin fi ife
Fi erin fi ife
Fi erin fi ife
Fi erin pade mi
Maa maa maa maa
Maa maa maa maa
Maaa se gbagbe mi
Fi erin fi ife
(pade mi)
Fi erin fi ife
Fi erin fi ife
Fi erin fi ife
Fi erin pade mi
(Oh oh oh)
(Uhuhuhuuuhuhuhuhuuu)
Oh oh uh uh
Oh oh oh
Uhuhuhuuuhuhuhuhuuu
Oh oh uh uh
Written by: Kafayat Quadri
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...