Credits

PERFORMING ARTISTS
Gbenga Akinfenwa
Gbenga Akinfenwa
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Gbenga Akinfenwa
Gbenga Akinfenwa
Songwriter

Lyrics

Jiji mo ji loni, Olorun o fiku pami
Ile o gbe mi mi, oro mi ma ja sope o eh
Mo tun jade loni, oni yi o je ko ye mi
Kori mi gbere bo o, gbona ara gbe mi ga o
Jiji mo ji tire tayo o (Jiji mo ji tire tayo)
Ire gbogbo ko wa mi wa o (Ire gbogbo ko wa mi wa)
Ogun orun ko yi mi ka o (Ogun orun ko yi mi ka)
Ogun esu o di atepa o (Ogun esu o di atepa)
Atepa, atepa, atepa o
Aso ofo o ti faya o (Aso ofo o ti faya)
L'aye mi, l'aye mi, l'aye mi
Fill me with your Holy fire o (Fill me with your Holy fire)
Emi kan sorire sere ni o (Mo n sorire sere)
Ire ati anu sare tele mi o (Mo n sorire sere)
Oju rere Oluwa lori ile mi (Mo n sorire sere)
Anu Oluwa lori ise mi o (Mo n sorire sere)
Ilekun ire ti si niwaju mi o (Mo n sorire sere)
Ogun ota ti ja, emi ti salo o (Mo n sorire sere)
Emi kan sorire sere ni o (Mo n sorire sere)
Written by: Gbenga Akinfenwa
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...