album cover
Onigbese
1,791
World
Onigbese was released on December 31, 2019 by Ziiki Media as a part of the album Onigbese - Single
album cover
Release DateDecember 31, 2019
LabelZiiki Media
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM119

Credits

PERFORMING ARTISTS
Mr. Real
Mr. Real
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Okafor Uchenna Victor
Okafor Uchenna Victor
Songwriter

Lyrics

To bá jẹ mi lowó
Ọ̀ga adé sanwó mi
Mà jẹ mi lowó
Mà jẹ gbèsè wọ 2020
Tè bá jẹ mi lowó
Aunty ẹ jọ ẹ sanwó mi
Mà jẹ mi lowó
Mà jẹ gbèsè wọ 2020
Oni gbèsè, àwọn onigbèsè
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè
Oni, oni gbèsè
Lati 2013, lẹ ti yá wó yì ṣẹ̀
This is 2019, you want to take it to 2020
Èmi n mo ko bá yín ní
Àbí wọn sépè fún yín?
Àwọn mà ṣha n fàní
Àwọn brother Jelili
Wọn lọ ṣi Quilox
Wọn tún lọ Cubana
Wọn lọ ṣi Pegas
Wọn gb'olosho
Wọn tún ṣe threesome
Élo lowó na tàn jẹ?
20 thousand péré
Wọn lọ ṣí party, wọn jó zanku
Ọlọ́run, ẹ ni pẹ kú
To bá jẹ mi lowó
Ọ̀ga adé sanwó mi
Mà jẹ mi lowó
Mà jẹ gbèsè wọ 2020
Tè bá jẹ mi lowó
Aunty ẹ jọ ẹ sanwó mi
Mà jẹ mi lowó
Mà jẹ gbèsè wọ 2020
Oni gbèsè, àwọn onigbèsè
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè
Oni, oni gbèsè
Dubai, Dubai
Wọn ti lọ wọn ti dé
Àwọn kàn yá wó lọ
Wọn ti dé wón ti n rànjú
Eh, who is your brother?
I don't know you no more
You wan borrow money?
20 thousand to yá, ò ti rí san!
Èmi n mo ko bá yín ní
Àbí wọn sépè fún yín?
Àwọn mà ṣha n fàní
Àwọn brother Jelili
Élo lowó na tàn jẹ?
20 thousand péré
Wọn lọ ṣí party, wọn jó zanku
Olorun, e ni pe ku
To bá jẹ mi lowó
Ọ̀ga adé sanwó mi
Mà jẹ mi lowó
Mà jẹ gbèsè wọ 2020
Tè bá jẹ mi lowó
Aunty ẹ jọ ẹ sanwó mi
Mà jẹ mi lowó
Mà jẹ gbèsè wọ 2020
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè, àwọn ọmọ onigbèsè
Oni gbèsè
Oni, oni gbèsè
Written by: Okafor Uchenna Victor
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...