album cover
Offerings
130
Christian & Gospel
Offerings was released on February 10, 2022 by apostledan.com as a part of the album Celestial Inspired Hymns & Songs, Volume 7
album cover
Release DateFebruary 10, 2022
Labelapostledan.com
LanguageEnglish
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM100

Credits

PERFORMING ARTISTS
Apostle Daniel Ekunola
Apostle Daniel Ekunola
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Apostle Daniel Ekunola
Apostle Daniel Ekunola
Songwriter

Lyrics

OFFERINGS
L/v: Elmorijah, Elmorijah
Olubukun ninu Ijo Mimo etc.
All: Elmorijah, Elmorijah
Olubukun ninu Ijo Mimo
Elberacad sokale sinu aye wa loni 2x
Seri ‘bukun Re, sori awa omo re
L/v: Olubukun ni o Oluwa, Oba mimo Isreali 2x
All: Elmorijah jowo o
Elmorijah wa bukun wa
Ibukun Re lawa ntoro laye
Eledumare wa gbe wa ga.
Elmorijah jowo o
Elmorijah wa bukun wa
Ibukun Orun lawa ntoro laye
Jesus Kristi wa gbe wa ga.
L/v: Nitoripe
All: Ire lo bukun, eye oju orun
Ire lo bukun , eja inu omi
Ire lo bukun, awon era ile
Eledumare wa gbe wag a
Ire lo bukun, eye oju orun
Ire lo bukun , eja inu omi
Ire lo bukun, awon era ile
Jesus Kristi wa gbe wa ga
L/v: Bukun wa oluwa
Maje ka lo lofo etc.
All: Bukun wa Oluwa
Maje ka lo lofo
Obukun Oshoffa 2x
Oluwa bukun wa
L/v: Omode nwoju Re
Silekun anu Re
Agba nwoju Re
Silekun anu Re
Ire lolubukun Ijo Mimo
Oluwa bukun wa
All: Bukun wa Oluwa
Maje ka lo lofo…etc.
All: Elberacad Beredeli
Oba Olubukun
Awa omo Re matunde o
Jowo bukun wa
Elberacad Beredeli
Oba Olubukun
Awa omo Re ma nwoju Re
Baba Bukun wa
L/v: ibukun Re lomuni la
Lai fi laalaa kun
Awa omo Re made o
Pese fun aini wa/ busi ise e wa
Awon omo kiniun ama salaini
Ebi asima pawon
Awa ta gbekele Oruko Re,
Ki ti o sai ni ohun to dara.
L/v: Elberacad Beredeli
Oba Olubukun
Awa omo Re ma njade lo
Seri ‘bukun sori ise wa
All: Elberacad Beredeli
Oba Olubukun ….etc
All: Jehova Ire lolubukun/3x
Elmorijah wa bukun wa.
Eng: Jehova You’re the one that bless /3x
Elmorijah come bless us all
Egun: Jeshovah oye we donano/3x 2x
Elmolijah wa dona mi
All: Jehova Ire lolubukun/3x
Elmorijah wa bukun wa.
All: Bukun wa /2x
Elmorijah sokale, bukun wa
Pese fun wa /2x
Jehova Jire Sokale
Pese fun wa
Wa gbewa ga /2x 2x
Jesu Kristi sokale
Wa gbewa ga
Ranwa lowo /2x
Emi mimo sokale
Ranwa lowo
All: Irin ajo, maba Jesu rinrinajo /3x
maba Jesu rinrin ajo
Ninu Ijo mimo
All: Irin ajo, maba Jesu rinrinajo /3x
maba Jesu rinrin ajo
kaye le yemi
L/v: Mose si
All: Mose siwa, losi Kanaan
Mose siwa, losi Kanaan
Alejo lawa nse, Awa arinrinajo
Mose siwa, losi Kanaan
Ope wa /3x
Ope wa si ‘jo Mimo 2x
Ope wa /3x
Ope wa si Celestial
L/V: Lomode Lagba
Esan ‘damewa yin 2x
All: Eyi lohun ti Jehova palase
All: San’damewa, san‘damewa re
Mase ja Olorun lole o
Ranti malaki ori keta 2x
Ese kesan de ikejila
L/v: Okunrin san damewa re
Obinrin san damewa re
Gbogbo enia esan damewa
Ase eledumare ni
Idamewa toku, jesu yio busi
All: San‘damewa, re
San‘damewa re
Idamesan toku 2x
Oluwa yio busi
L/v: Mu ‘damewa re wa
All: Ase Oluwa ni
Idamesan toku 2x
Oluwa yio busi
L/v: Maba lo o, ile ologo
Maba lo o, ile alayo
All: Baraye komi, Maba Jesu yi lo 2x
Baraye komi, Maba Jesu wole ogo
L/v: Isura mi wa nibe
All: Isura mi wa nibe odaju 5x
L/v: Oti daju pe nho layo
Lojo ti mo ba dele
All: Motito Isura mi jo sile Ologo
Motito Isura mi jo sile Alayo
Odajupe ‘pe nho layo 2x
Lojo timo ba dele
L/v: Odaju pe nho layo
Lojo timo ba dele
All: Odaju pen ho layo
Lojo timo ba dele 4x
L/v: Kole o kole
All: kole sori apata 2x
L/v: Nitoripe
All: Ile Iyanrin, aba yanrin lo 3x
Kole sori apata
L/v: Olubukun
All: Olubukun ni o OLuwa
Oba mino Israeli 2x
Wa bukun wa
All: Benevolent art thou Oh Lord
Holy King of the Israelites 2x
Come bless us all
All: Dona nor we ye Okluno
Aholu wiwe isleli ton 2x
Wa dona mi
Interlude (jamia)
All: Olubukun ni O Oluwa
Oba mimo Israeli
Wa bukun wa
Written by: Apostle Daniel Ekunola
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...