album cover
INSIDE LIFE
28
Afro-Beat
INSIDE LIFE was released on July 20, 2022 by Chabalaja as a part of the album INSIDE LIFE - Single
album cover
Release DateJuly 20, 2022
LabelChabalaja
LanguageEnglish
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM103

Music Video

Music Video

Credits

COMPOSITION & LYRICS
Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
Songwriter

Lyrics

Bàbá Ọmọ Ẹ̀mí Mímọ́ mo dé
Ṣọ́ mi as I dey kebu dey paro lo Inside life save me
Ọlọ́run mi jẹ́ kí n rí bátíṣẹ́
Ọlọ́run mi ò
Dákún, máa ṣe jẹ kí ọmọ ológò tàráká láìyé láìyé
Mótí jawo ninu sipanpala
Free me now if I sing Apala
Mótí fẹ́ báwọn ṣọ̀ dá'awada
Koto dipe má mú ẹ̀yí tó jẹ́ bàbárà wá
Irẹ ni mo pe
Ayọ ni mo pe
Kò má tọ́ mí wá
Àwọn tí mo ń pè
Èèyàn Olú Mòòṣe
Kan bān fi ẹ̀mí ṣọ́na
Lyrically mo máa forin dábíra
Ṣé ńgbọ́ mi dáadáa?
Boy wey dey para pass paracetamol
Emo pọ̀lómọ́ loloja
Them fit dey blow their whistle
Aagbooo
I'm here to blow your mind away with my Kákàákí
Killing every beat no pistol
Take market oya pick two
Lórítítí kaje kiso
Ọmọ tó fẹ́ lówó kọ́ dé ni sun
So me wake up till the midnight
Ọmọ òlógò just wanna feel fly
Me wanna make ham inside this life
Cos I gat one life to live
Bàbá ọmọ Ẹ̀mí Mímọ́ mo dé
Ṣọ́ mi as I dey kebu dey paro lo Inside life save me
Ọlọ́run mi jẹ́ kí n rí bátíṣẹ́
Dákún Baba mi o
Dákún, máa ṣe jẹ kí ọmọ ológò tàráká láìyé láìyé
Arúgbó jẹ́ gbèsè
But Òmò Àrùgbó tà gèlè
Eni tó bá ti jèrè, lọ́mọ aráyé ń ta gèlè fún
O lotta song me I sing ehn
Kín lè pàwò kishi
Yaya ya
Nobody dey pity
If I no get shishi
So I hustle on my birthday, and the 364
Abe ri
As I dey hustle I dey pray Halleluyah Jericho ti fall
Ẹ̀ mọ̀ pé mi ò fo
Mòfé káyé mọ́ mí
But ìlú ayé yìí, Temple run ni
Go alone tell nobody
If you wanna be somebody
Awada kọ, If I dey fa so la ti do do go cause kasala
Haha eh
Bàbá Ọmọ Ẹ̀mí Mímọ́ mo dé
Ṣọ́ mi as I dey kebu dey paro lo Inside life save me
Ọlọ́run mi jẹ́ kí n rí bátíṣẹ́
Ọlọ́run mi ò
Dákún, máa ṣe jẹ kí ọmọ ológò tàráká láìyé láìyé
Má má jẹ́ n kú sori mo ṣe ṣe ṣe
Ojó típẹ́ mo ti ń bọ̀
Tey tey tey
Inside life
Written by: Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...