Lyrics

Yor-yor, yor, ahn-ahn Moti kor hip-hop, moti kor reggae Odayan mo, ola emi kor yeye Beremi lowo awon ton tin gbọ tey-tey Ata awon morufa idigan l'ebe Bíi moo shey funwon, lon pariwo Chineke Faluya funwon bíi Sunny Nnweke Oromo Adiye, Asha Suregbe Environmental, awa tunlese Emi lala gbé, eyin lele gbé Emi lala dura, eyin lelepe Eyi tatun bebe, otun peleke Awon olorin wẹwẹwẹ, won tii ferege (Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa) (Talosope whyning, okin se fiipa) (Won ni talo loyun too wa ninu abiba) (Woo, Brother you fit ask ifa) (Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa) (Talosope whyning, okin se fiipa) (Won ni talo loyun too wa ninu abiba) (Woo, brother you fit ask ifa) Anytime wey I pull up Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ, o'tilọ jor Them they ask make I do more ya-ya-ya Anytime wey I pull up Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ, o'tilọ seh Them they ask make I do more ya-ya-ya (Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium (Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, oya s'ope o'tilọ) escolopidium (Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium (Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, oya s'ope o'tilọ) escolopidium Wizzy be like person wey don take banku He dey carry them trabaye Bawo lon shey shey ee ṣàlàyé Ọmọ tẹti fojú dii yen mamare Moo ti fobo gan, motion gbogbọn gan Motii fobo gan Moti lọwọ kan Salawa break my heart, moo dẹ fii ṣọkan Moti showo kan, kọ tóo fii f'okọ Moní gangan sọ, lọ multi Sponsor Bíi ajey tẹ R2, lòó Shege tẹ cursor Emi ọmọ ton sọ, too tun taa san san Ọwọ tóo fii fọ ata,.má fii fobo pọn (Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa) (Talosope whyning, okin se fiipa) (Won ni talo loyun too wa ninu abiba) (Woo, Brother you fit ask ifa) (Eni òríyọ, Iyen tii jẹ home training pa) (Talosope whyning, Okin se fiipa) (Won ni talo loyun too wa ninu abiba) (Woo, Brother you fit ask ifa) Anytime wey I pull up Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ (o'tilọ jor) Them they ask make I do More ya-ya-ya Anytime wey I pull up Wọn máa kuu lọ oya s'ope o'tilọ (o'tilọ seh) Them they ask make I do More yayaya (Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium (Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ) escolopidium (Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium (Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ) escolopidium (Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium (Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ) (Ola funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa jẹ jor, koo to) escolopidium (Olorin funwa jẹ jor funwa jẹ jor funwa je jor, Oya s'ope o'tilọ) escolopidium You dey use your future to play You dey use your generation to play You dey use your next generation to play You are doing rubbish, the things dar you are doing good You are doing lunatic, lunatic escolopidium Picaluculation of Jijatical
Writer(s): Oladipupo Olabode Oladimeji Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out