album cover
Tesumole
album cover
00:00
00:05
00:10
00:30
00:45
00:50
01:10
01:35
01:45
02:05
02:15
02:30
03:15
00:00
03:28
Past 7 Days
Tesumole was discovered most frequently in the first few seconds of the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Intro]
Hello
Marlians
[Chorus]
Ṣebi omo Jesu niwo
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
Gbẹsẹ na
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
Ṣebi omo Jesu niwo
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
Gbẹsẹ na
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
T'Eṣu mọlẹ, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ (Chinedu t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ (Amaka t'Eṣu mọlẹ)
T'Eṣu mọlẹ, wa ṣa le t'Eṣu mọlẹ (Chigozie t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, iwo ṣa t'Eṣu mọlẹ (Nnamdi t'Eṣu mọlẹ)
[Verse 1]
Ṣo mo Da Cõsta?
O n wo 10 bi ti Okocha
Abi osun, ṣebi iya e ni pe o mo'gbo fa
Ma lo fa o, It's not for children ma lo fa
O lo far, o lo jinna, o lo far (O lo far)
Awa wa o, awon ni k'on ma lo wa
T'on ba wa, awa naa ṣa l'on ma ba
Ojo to ro ni Ibadan lo ka pata
Igba tojo ro lale ana o bo pata
[Verse 2]
Abi iwo naa can sing?
Set awon Beyonce
Omo t'on so
Why are you acting like you can't see
See that bakasi
Make a man want to crash
After show, after show is the after party
44-4, awa 40, 19-1, awon 18
Marlian ma la wa, won fe yo J ninu Jesu fun wa
[Verse 3]
Mo fine, there is nothing wrong
Money is getting long
My hair is getting long
Kini abe mi gan-an is getting long
[Chorus]
Ṣebi omo Jesu niwo
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
Gbẹsẹ na
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
Ṣebi omo Jesu niwo
Gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ
Gbẹsẹ na, gbẹsẹ ko te
T'Eṣu mọlẹ, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ (Chinedu t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ (Amaka t'Eṣu mọlẹ)
T'Eṣu mọlẹ, wa ṣa le t'Eṣu mọlẹ (Chigozie t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, iwo ṣa t'Eṣu mọlẹ (Nnamdi t'Eṣu mọlẹ)
[Verse 4]
Ke e be, ke e ku
Ke demo, ke panyi
Eyin naa o ni fe lo
Te ba pe wa gan-an e ni pelo
E dese fun
E ṣeka fun
Eyin, ti o ba wole ke lo oko fun
[Chorus]
T'Eṣu mọlẹ, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ (Chinedu t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ (Amaka t'Eṣu mọlẹ)
T'Eṣu mọlẹ, wa ṣa le t'Eṣu mọlẹ (Chigozie t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, iwo ṣa t'Eṣu mọlẹ (Nnamdi t'Eṣu mọlẹ)
T'Eṣu mọlẹ, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ(Chinedu t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, gbẹsẹ ko t'Eṣu mọlẹ(Amaka t'Eṣu mọlẹ)
T'Eṣu mọlẹ, wa ṣa le t'Eṣu mọlẹ (Chigozie t'Eṣu mọlẹ)
Gbẹsẹ na, iwo ṣa t'Eṣu mọlẹ (Nnamdi t'Eṣu mọlẹ)
Written by: Azeez Fashola, Chisom Ezeh
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...