Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Zlatan
Performer
Seyi Vibez
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Omoniyi Temidayo Raphael
Songwriter
Oluwaloseyi Afolabi Balogun
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Dibs
Producer
Lyrics
[Verse 1]
Billion dollar baby ọmọ dudu bi koro iṣin
Wọn fẹ la mi ẹ gba mi, I don dey see screenshot
Factory reset put in order
Laakaye mi o ni jọba
P***y cat put in Russia
Simultaneous equation gats balance
5x 4y, assignment for those wey dey doubt me
[Verse 2]
O jabọ ti sẹ ọmọ na bouncing
Irawọ ni mi yọgo oju riran if you can't see
N gbọ ṣo ni one billion to le ya mi?
I no dey put my mouth for anything wey no concern me
Wọn fẹ yọ sọ, o ya pẹnumọ
Idọti kẹ, iwọsi kẹ, ṣe iyẹn lọmọ ologo ma faramọ
Mo darun mọju mo ṣe gara tan
Shoe gbẹngbẹ Balienciaga lẹsẹ, ọmọ ologo gara lọ
[Verse 3]
Mo bẹyin tori anọbi Baba Fa', Baba Fa', Fatima
Jẹ ki n mọ bo ṣe n lọ
Mo fẹ debẹ, jẹ ki n pọnke
Once debẹ is debẹ for life o ti ye ẹ ẹ ẹ
Mi casa, su casa
Idan ọmọde ko ni lamba
Rayban Abacha, abracadabra
Propaganda ilara pupọ
Ko sohun toburu
Fila ori were bi t'Adedibu
[Verse 4]
Ogo tanna tanna
Let there be light tan ba pana wọn
Asalatu janmọ
Ti n ba lọ emi ma mọmọ
Ogo tanna tanna
Let there be light tan ba pana wọn
Asalatu janmọ
Ti n ba lọ emi ma mọmọ
[Chorus]
T'epo sori eṣu
F'aja bọ ogun
Gbẹbọ sorita
O lọ church
O lọ mosque
Money is a must lọmọ oro ṣe n kanra
O dẹ bego lori meji o fẹ fomi owo ṣanra
Print out de Monaco fẹrọ pẹsẹ jaye, aye to dun, aye to palazzo
Ko si time o fẹ fi million dollar r'aago
Mo fẹ wo balance ki n bu sẹrin ki n ni k'ọn ba mi yigbo
No girl wants a broke n***a
O wọ ankara o jẹ semo tẹpamọṣẹ n***a
Awọn tan wo mi t'ọn ni ki n wa bigba
Lọla ọlọpẹ rẹ ko saye fun yin awọn men mi da
[Verse 5]
Mo bẹyin tori anọbi Baba Fa', Baba Fa', Fatima
Jẹ ki n mọ bo ṣe n lọ
Mo fẹ debẹ, jẹ ki n pọnke
Once debẹ is debẹ for life o ti ye ẹ ẹ ẹ
Mi casa, su casa
Idan ọmọde ko ni lamba
Rayban Abacha, abracadabra
Propaganda ilara pupọ
Ko sohun toburu
Fila ori were bi t'Adedibu
[PreChorus]
Ogo tanna tanna
Let there be light tan ba pana wọn
Asalatu janmọ
Ti n ba lọ emi ma mọmọ
Ogo tanna tanna
Let there be light tan ba pana wọn
Asalatu janmọ
Ti n ba lọ emi ma mọmọ
[Chorus]
Ogo tanna tanna
Let there be light tan ba pana wọn
Asalatu janmọ
Ti n ba lọ emi ma mọmọ
Ogo tanna tanna
Let there be light tan ba pana wọn
Asalatu janmọ
Ti n ba lọ emi ma mọmọ
Written by: Omoniyi Temidayo Raphael, Seyi Vibez