Lyrics

Hallelujah ni won ma ko Hallelujah si wo olurun mi Orin hallelujah ni woo bawon torun ko o Oju orun fun dede Awo San man ni Pele ni pele Eru lo fi ko aye Okun fun ajara Eda o yanbo Awo Ewo lo da Ara oto to MO korin hallelujah si wo tan awon Orun bo o Mimo Mimo ni won ke Awon ti Eda orun angeli lowo lowoo Won fi ojo jo fi ori bale o Agba gba n ke Mimo Si oludande aye gbogbo Hallelujah si oni ite ogo aditu Gbogboro owo to na aye ja lati inu orun wa Kikorin won o dake ri Si olurun awon omo ogun Hallelujah ni won ko Won segun aye ko si daru dapo Owun gbo lo Leto leto Ebi ko pa won ri beeni Ara ko ni won ri Kida ayo ekunrere alafia Awa ti a le ke hallelujah ninu aye Awa lafi Orin isegun se wa logo A o Jeri Ota a di Eni ite mole pata Orin hallelujah ni a fi ba Jesu joba Awa ti a gbala
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out