album cover
Ope
Singer/Songwriter
Ope was released on June 25, 2023 by Nlvibes as a part of the album Ope - Single
album cover
Release DateJune 25, 2023
LabelNlvibes
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM143

Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Beejay praise
Beejay praise
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Omobolaji Abigeal
Omobolaji Abigeal
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Dr. Groove
Dr. Groove
Producer

Lyrics

Ope Iyin f\'Olorun loke
Oba to n sohun gbogbo lodulodu
Efope fun Oluwa nitori ti o seun, nitori anu re duro titi lailai
Iyin fun Oluwa, Ope fun Oluwa, Abiamo toto, ti wo omo lawoye o, olutoju mi, atileyin aye mi, Olorun iwo ni opo to sole aye mi ro
Ogo ye le re, iyin f\'oruko re, opomulero aye mi o je n jabo, loju aronipin o so Egan mi dogo, gbogbo imo ota Lori mi o dofo o, kani kosi Jesu funmi, iji aye iba ti gbe mi lo, iyin ye o o, oba abanigberu dori
O je olododo nigbogbo ona re, oro to ba te nu re jade dandan ni ase, fun gbogbo imuse ileri re o Lori aye mi, emi taye ti ropin o so mi dogo pataki, ose Oluwa abanimule madani
Ebami yin, Ebami gbe ga, Ebami yin atobiju, Ebami gbo\'luwa ga
Written by: Omobolaji Abigeal
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...