album cover

Alaye

60,743World2010
album cover
00:00
00:05
00:30
00:40
00:55
02:05
02:15
02:30
02:35
02:40
02:45
03:05
03:10
03:15
00:00
03:36
Past 7 Days
Alaye was discovered most frequently at around 40 seconds into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

Oh, oh, oh-oh-oh
Edlyne Records, yup
Ẹ ṣẹ́ o
Ẹ mú jó, ẹ ṣẹ́ o
Kò mọ lẹ́, lẹ́, lẹ́ (Ọ̀ṣẹ́)
Kò mọ lẹ́, lẹ́, lẹ́
Má lọ fara wé mi o (Ṣó gbọ́ ẹ?)
Ó ní fẹ́ gba ojú aláyé mi o (Ọ̀ṣẹ́)
Lójójúmọ́ ayé, gbogbo ayé ni o (Ẹ gbàgbé òṣì)
LKT lórí TV àti radio (Radio o), ye
Ẹ máa wo káká ẹ (Eh-eh)
Mo gbádùn bó ṣe ń ṣe báka ẹ (Eh)
Jẹ́ ká wá lọ ló ìyára ẹ (Eh-eh)
If only mo máa máa rà ẹ, yeah
One time you hear my shawty
When you hear the beat, make you shake your body
Celebrities plenty for this my party
Ọmọde yìí, jọ́, rọra gbọ́n dí, gbọ́n dí (Ye)
Wọ́n wá mi lá mẹ́ gan o
Mo ti pè bí Ṣọ́nẹ́kan o
Akóyìn sí ẹ bí Faragon o
This our march na marathon o (Ye-ye)
Ye, wọ́n wá mi lá mẹ́ gan o
Mo ti pè bí Ṣọ́nẹ́kan o
Akóyìn sí ẹ bí Faragon o
Ọmọ, this our march na marathon
Má lọ fara wé mi o (Ṣó gbọ́ ẹ?)
Ó ní fẹ́ gba ojú aláyé mi o (Ọ̀ṣẹ́)
Lójójúmọ́ ayé, gbogbo ayé ni o (Ẹ gbàgbé òṣì)
LKT lórí TV àti radio (Radio o), ye
Ẹ máa wo káká ẹ (Eh-eh)
Mo gbádùn bó ṣe ń ṣe báka ẹ (Eh)
Jẹ́ ká wá lọ ló ìyára ẹ (Eh-eh)
If only mo máa máa rà ẹ, yeah
Omo, ah, I touch you, gosh
Ọlọ́hun, I no go rush
Ó kì n ṣe ọmọde, no dey blush
Rọra, má pariwo, oh my gosh
Tí mo bá ti lùlú ẹ, kò máa dùn
Gorodome, ẹ má kún
Ọmọ, àpò mi ti wú
Jẹ́ ká má lọ, kò se wù
Meeny, meeny, miny mo
Tí n bá play, mo máa n goal
As I dey ball, emi omiro
Naija àti Yankee, wọ́n máa rí show
Má lọ fara wé mi o (Ye-ye, ṣó gbọ́ ẹ?)
Ó ní fẹ́ gba ojú aláyé mi o (Ọ̀ṣámọ́)
Lójójúmọ́ ayé, gbogbo ayé ni o (Gbogbo ayé, ẹ gbàgbé òṣì)
LKT lórí TV àti radio (Radio o, ẹ gbàgbé òṣì), ye
Ẹ máa wo káká ẹ (Eh-eh)
Mo gbádùn bó ṣe ń ṣe báka ẹ (Eh)
Jẹ́ ká wá lọ ló ìyára ẹ (Eh-eh)
If only mo máa máa rà ẹ, yeah
Let me see you get down low, oh-oh
Let me see you get down low, low, low, low, low
1-2, buckle my shoe
3-4, knock at the door
Uncle, what you gonna do?
LKT, you don hear am before
Ye, wọ́n wá mi lá mẹ́ gan o
Mo ti pè bí Ṣọ́nẹ́kan o
Akóyìn sí ẹ bí Faragon o
Ọmọ, this our march na marathon
Má lọ fara wé mi o (Ṣó gbọ́ ẹ?)
Ó ní fẹ́ gba ojú aláyé mi o (Ọ̀ṣẹ́)
Lójójúmọ́ ayé, gbogbo ayé ni o (Ẹ gbàgbé òṣì)
LKT lórí TV àti radio (Radio o), ye
Ẹ máa wo káká ẹ (Eh-eh)
Mo gbádùn bó ṣe ń ṣe báka ẹ (Eh)
Jẹ́ ká wá lọ ló ìyára ẹ (Eh-eh)
If only mo máa máa rà ẹ, yeah
Má lọ fara wé mi o (Ṣó gbọ́ ẹ?)
Ó ní fẹ́ gba ojú aláyé mi o (Ọ̀ṣẹ́)
Lójójúmọ́ ayé, gbogbo ayé ni o (Ẹ gbàgbé òṣì)
LKT lórí TV àti radio (Radio o), ye
Ẹ máa wo káká ẹ (Eh-eh)
Mo gbádùn bó ṣe ń ṣe báka ẹ (Eh)
Jẹ́ ká wá lọ ló ìyára ẹ (Eh-eh)
If only mo máa máa rà ẹ, yeah
Written by: Olalekan Olayade

Shazam Footer

Select language:
Google Play Store
Apple App Store
Chrome Web Store
Galaxy Store

Follow Us

Loading...