album cover
Wonder
6,744
World
Wonder was released on June 30, 2023 by Dvpper Digital as a part of the album Barry Back 2 - EP
album cover
Release DateJune 30, 2023
LabelDvpper Digital
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM117

Credits

PERFORMING ARTISTS
Barry Jhay
Barry Jhay
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Barry Jhay
Barry Jhay
Composer

Lyrics

[Intro]
Take it or not I’m blessed
Ṣẹ gbọ? Oh yes
And no son of man
Can take my joy away
[Verse 1]
Wetin be my own no go pass me by
Ẹkun ati oṣi bye bye
Tẹ ba ro pe ẹ n ṣe mi Atanda
Ara yin lẹ n ṣe
[Verse 2]
Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
Di horror mọ wọn lọwọ
K'ọn ma ba a sọ pe "Temi bawo"
Ni mo fi sun ṣokoto
Ẹ ma lu kan pa tẹ ba fọmọwọmọ
And e no get where e touch (Aje aje)
Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
[Verse 3]
Kiamọsa ni ko tete
Ma tori mi lọ jẹ gbese
Anoti anoti allele
Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
Ọmọ araye le ya'yan ni were
Psycho pọ lode
Awọn le mọ le ṣe
Eni to mon eniyan lon s'ese eniyan o
[Verse 4]
Afopina to loun o pa fitila
To loun o pa fitila ara ẹ ni o pa
Itakun to ni kerin ma wọdo
To ni kerin ma wọdo wọdo
Toun terin ni wọn jọ lọ (Aya)
[Verse 5]
Mo ti lọ bọ mọ wọn lọwọ
Di horror mọ wọn lọwọ
K'ọn ma ba sọ pe temi bawo
Ni mo fi sun ṣokoto
Ẹ ma lu kan pa tẹ ba fọmọwọmọ
And e no get where e touch (Aje aje)
Ladugbo yin emi l'ọn gbọ
Orin wa l'ọn n jẹ nigboro
[Verse 6]
Kiamọsa ni ko tete
Ma tori mi lọ jẹ gbese
Anoti anoti allele
Ẹni wuwa epe lo ma gbepe
Ọmọ araye le ya'yan ni were
Psycho pọ lode
Awọn le mọ le ṣe
Ẹni to mọ eniyan lo le ṣ'eniyan o
Itakun to ni kerin ma wọdo
To ni kerin ma wọdo wọdo
Toun terin ni wọn jọ lọ
Written by: Barry Jhay
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...