album cover
Ope Mi
1
Christian & Gospel
Ope Mi was released on October 27, 2023 by Dvpper Digital as a part of the album Irawo tuntun - EP
album cover
Release DateOctober 27, 2023
LabelDvpper Digital
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM109

Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Mr Shoro
Mr Shoro
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Ilebe Oluwasegun Joshua
Ilebe Oluwasegun Joshua
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Tobmax
Tobmax
Producer

Lyrics

Ope ope o ope mi re baba dada
Ope ope o ope mi re olu orun
Ope ope o ope mi re baba dada
 
Ope ope o ope mi re olu orun
 
Instunental
Ope ope o ope mi re baba dada
 
Ope ope o ope mi re olu orun
 
Ope ope o ope mi re baba dada
 
Ope ope o ope mi re olu orun
 Solo:
Ese eee ooo olorun mi ese o
Wiwa l'aye mi doni igoni fun oruko re, wiwa l'aye doni iyin ni fun oruko re, opo egbe won ti ku, opo egbe mi won ti lo, loje kin mu ope mi wa fun adani waye oseun, ope ope o ope re mom'ope wa, ope ope o ope re baba oseun
Instrumental solo:
B'ori ba pe Nile dandan kodire, mowad'alayo modi onijo niwaju baba mi
Emi labata k'a fi ratupa mowad'alayo ninu oluwa, iwo lotosi iwo niyin ye, iwo lotosi iwo niyin ye, olorun gba gbogbo ogo
Chorus: ope ope o ope mi re baba dada ope mi re olu orun
Solo: efi ope fun oluwa nitori tio seun, nitori ti anu re duro Lori wa, amo ibi t'ati bere tele, amo ibi ti aba de... Atun mo ibi giga tio mu wa lo o, eyi lo mu wa dupe, segun nabi amoore, eyi lomu wa dupe shoro amoore, o se olorun tubo maase Bebe lo.
O se olorun tubo maase Bebe lo.
Imo ota ni pe k'owo oun tio ti duro, imo ota ni pe kio tuka oun tio oti pari,
Eseun olorun ti eje ki ota ba oju wa je...
Adupe oreeee o
Ese
Adupe oreeee baba amupe wa
Ba ope wa adupe
Ba ope wa adupe
Ope ope o baba dada
Ope ope o oluorun
Ope ope ope o baba dada oluorun
Ope ope o baba dada
Ope ope o oluorun
Ope ope ope o baba dada oluorun
Written by: Ilebe Oluwasegun Joshua
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...