album cover
Gbemidebe (feat. Qdot)
101,979
Music
Gbemidebe (feat. Qdot) was released on March 31, 2022 by Dvpper Digital as a part of the album Gbemidebe (feat. Qdot) - Single
album cover
Most Popular
Past 7 Days
00:00 - 00:05
Gbemidebe (feat. Qdot) was discovered most frequently in the first few seconds of the song during the past week
00:00
00:10
00:15
00:25
00:40
00:55
01:00
01:20
01:30
01:35
01:40
02:30
00:00
02:58

Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Dj OP Dot
Dj OP Dot
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Opeyemi Oladipupo soidiq
Opeyemi Oladipupo soidiq
Songwriter

Lyrics

[Intro]
OP Dot, gbe wa lọ oh (2T Upon The Beat)
Ọmọọmọ Mọriamọ (DJ OP Dot, I love you)
Alagbe
Qdot lorukọ mi
Ti n ba ni "gbetiti, gbetiti gbe gbe"
[Verse 1]
(Gbe mi debẹ)
Ki l'ọn jẹ, ta a jẹ ri? (Gbe mi debẹ)
Packagin' lo pa Lekki (Gbe mi debẹ)
Wọn ni o zeh k'ọn to zehri (Gbe mi debẹ)
Ko si barber ti o le gẹri (Gbe mi debẹ)
Haircut lo ma yatọ (Gbe mi debẹ)
Happy Hour lori Molly (Gbe mi debẹ)
Idunnu lo ṣubu layọ (Gbe mi debẹ)
Alagbe le ṣalaye (Gbe mi debẹ)
O n gbe mi trabaye (Gbe mi debẹ)
Irọlẹ lo ma n wẹ (Gbe mi debẹ)
Awọn ọmọ mi loruloru (Gbe mi debẹ)
Kafaya (Gbe mi debẹ)
Karimo (Gbe mi debẹ)
Jennifer (Gbe mi debẹ)
Ori mi lo fẹ fa (Gbe mi debẹ)
Alhaja Memuna (Gbe mi debẹ)
Ẹlẹha to n ṣe stripper (Gbe mi debẹ)
Awa o ki n nawo fun eegun (Gbe mi debẹ)
Bẹ ṣe n daṣọ boju (Gbe mi debẹ)
Akọrikọda (Gbe mi debẹ)
Buju ti p'orukọ da (Gbe mi debẹ)
O d'ori o d'ori (Gbe mi debẹ)
Alhaja loun o bori (Gbe mi debẹ)
O gbowo, ko fẹ ṣori (Gbe mi debẹ)
Mo mọ po mọ mi (Gbe mi debẹ)
Lo ṣe n fọbọ lọ mi (Gbe mi debẹ)
Lọ bere mi nilu Ibadan (Gbe mi debẹ)
Wọn ma jẹ ko mọtan (Gbe mi debẹ)
Igboro mọ mi (Gbe mi debẹ)
Igboho Ooṣa gan-an mọ mi (Gbe mi debẹ)
Ọmọ anibọn ma jale (Gbe mi debẹ)
Ọmọ ajale ma gbowo (Gbe mi debẹ)
O rọrun mi ni? (Gbe mi debẹ)
O ri panpa? (Gbe mi debẹ)
Idi nla gbangba (Gbe mi debẹ)
Ko niṣẹ lapa (Gbe mi debẹ)
Ẹni t'ọn bọ, to n bọ aja (Gbe mi debẹ)
Ti picker ba gbowo lọ (Gbe mi debẹ)
Middle man lo jẹ gbese (Gbe mi debẹ)
B'ebi ba pa were (Gbe mi debẹ)
Were ma ja wọja (Gbe mi debẹ)
Eegun ara ọrun (Gbe mi debẹ)
Oun gan-an hustle laye (Gbe mi debẹ)
Trust nobody (Gbe mi debẹ)
Olamide ko mọnu Enimoney (Gbe mi debẹ)
Ninu aye wọn joju anybody (Gbe mi debẹ)
[Verse 2]
IBD Dende (Gbe mi debẹ)
Alaye ma n gbe mi de'bẹ (Gbe mi debẹ)
MC Oluomo (Gbe mi debẹ)
L'Eko ile, ọmọjọmọ (Gbe mi debẹ)
Arowolo lo n ta mọto (Gbe mi debẹ)
Nilu Atlanta (Gbe mi debẹ)
Ẹ ba n ki Mama Kay oh (Gbe mi debẹ)
Mummy OP Dot (Gbe mi debẹ)
Eeyan Qdot (Gbe mi debẹ)
Mayegun gbogbo Dubai (Gbe mi debẹ)
Ijebu o fowo ṣere (Gbe mi debẹ)
Wọn o fiṣẹ ṣere (Gbe mi debẹ)
Mo mọ Tunde Adigun (Gbe mi debẹ)
Adigun, Abulẹṣowo (Gbe mi debẹ)
Kogbagidi (Gbe mi debẹ)
Billique 60, 40 (Gbe mi debẹ)
Bukunmi, Mama Meto (Gbe mi debẹ)
Climax lo n ṣe visa (Gbe mi debẹ)
Dakun, ma ṣe transfer (Gbe mi debẹ)
Kala (Gbe mi debẹ)
Ranju (Gbe mi debẹ)
Akala gbogbo Golo (Gbe mi debẹ)
Mo mọ alaṣẹ gbogbo Turkey (Gbe mi debẹ)
Otunba Cash (Gbe mi debẹ)
Mo mọ Sanwo Ayanlu (Gbe mi debẹ)
Akinrogun, owo mi da? (Gbe mi debẹ)
Mo ni mo mọ'Ija ọmọde (Gbe mi debẹ)
Eeyan Okoko (Gbe mi debẹ)
Okoko dakun, ma yinbọn (Gbe mi debẹ)
Kunle Poly (Gbe mi debẹ)
Eeyan Barry Shine (Gbe mi debẹ)
Gbe mi debẹ (Gbe mi debẹ)
Onimọto gbe mi sare (Gbe mi debẹ)
OP Dot, gbe mi debẹ
2T, gbe mi debẹ
(2T on the Mix)
Written by: Opeyemi Oladipupo soidiq
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...