album cover
Dessigna
3,966
Worldwide
Dessigna was released on November 29, 2023 by Ziiki Media as a part of the album Dessigna + Italia - Single
album cover
Release DateNovember 29, 2023
LabelZiiki Media
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM68

Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Idowest
Idowest
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Jimoh idowu wasiu
Jimoh idowu wasiu
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
afrostiqs
afrostiqs
Producer

Lyrics

[Chorus]
Designer, designer
Designer, designer I'm feeling Gabbana (Designer, designer I'm felling Gabbana)
She came from Botswana
She rocking the Gucci, the Dolce Gabbana
Like a Tony Montana
The told me that Gaza be stealing some azzah
Mi o bẹru karma
Mafia a yigi di yigi di yaga
[Verse 1]
Two sum l'Addis Ababa
Awọn ọmọ mi atata
Gba bẹ wọnu UK tori wọn mọ mi ni Turkey pẹlu awọn agbaagba
Wọn gbọ mi ni Casablanca, wọ Canada mo lawọn abaṣa
Idowu ologo daya
Pull up ninu Benz olodo rabata
Wọn ni pe ọn wa mi ni SA
Tori mo ṣe USA
Awọn onidii rabata, ọlọmọ kan ki lẹ n wa ULE
Wọn gbe ẹ lọmọ paranran (Ko kan aye)
Iyawo ẹ need CLA
Mo wa ninu GLK ko to gbọmọ fun mi a ma ṣe DNA
Designer, designer
Designer, designer I'm feeling Gabbana (Designer, designer I'm felling Gabbana)
She came from Botswana
She rocking the Gucci, the Dolce Gabbana
Like a Tony Montana
The told me that Gaza be stealing some azzah
Mi o bẹru karma
Mafia a yigi di yigi di yaga
[Verse 2]
Ma pe mi lọmọ lile
Okutiyẹbọ toke tilẹ ti mo ṣa si tilẹ yii kọ
Fọpa tilẹ tilẹ bi jagaban, 10 girls in my carba
Were wa bi ti Hassan
Mafia ti ja yin to, have been carry tone
Wọn dẹ fẹ ja mi bi Sosoliso
Adegbeju balẹ sinu Euro
Man U nayan pa ni Dodolido
[Verse 3]
Two sum l'Addis Ababa
Awọn ọmọ mi atata
Gba bẹ wọnu UK tori wọn mọ mi ni Turkey pẹlu awọn agbaagba
Wọn gbọ mi ni Casablanca, wọ Canada mo lawọn abaṣa
Idowu ologo daya
Pull up ninu Benz olodo rabata
[Chorus]
Designer, designer
Designer, designer I'm feeling Gabbana (Designer, designer I'm felling Gabbana)
She came from Botswana
She rocking the Gucci, the Dolce Gabbana
Like a Tony Montana
The told me that Gaza be stealing some azzah
Written by: Jimoh idowu wasiu
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...