Lyrics

(Yo D') Quality over quantity (o pree) Oò mọ 'rú ẹ', ṣọ' ọ ní 'rú ẹ? Ẹjẹblejẹ, ẹ'jẹ ló ń lò, oh no Ọmọ tó ní ìyá òun ò ní sùn, ohùn gangan ò ní sinmi And as I dey tẹpá mọ my hustle, ẹ fún Adekunle mi ní Simi Ara lamọ, ara lamọ (lamọ), a ò mọ ẹni tó fẹ' ni dénú (ye) Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fi Bíbélì ka kéwú Ara lamọ, ara lamọ (lamọ), a ò mọ ẹni tó fẹ ni dénú (ye) Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fẹ fi Bíbélì ka kéwú Confirm ni, no be para oh Control, no be galala To make money, no be by dragger Oh-oh-oh, aya-ya Confirm ni, no be paara oh Control, no be galala To make money, no be by dragger Oh-oh-oh, aya-ya (aya-ya) Heys, ọmọ tó bá ta féleféle, ẹ gbá ojú ẹ Ẹ le pa (ẹ le pa), ó le kwà (ó le kwà), oh-uh-oh Ọmọ tó bá bẹ sí mi, éè ní fara ire lọ, àh Ajurawalọ, ti ìjàkadì kọ, ìwọ náà mọ Ẹni bínú mi, ò ní ní sinmi Ẹ'yin enemies, kakulu fuhi Yes, I mean dede yín, uh Mo sorry fún gbo-, gbo yín oh-oh Mo sorry fún gbogbo yín lọ'kọ'ọ'kan (ah-yeah) Confirm ni, no be para oh Control, no be galala To make money, no be by dragger (yeah, ye) Oh-oh-oh, aya-ya Confirm ni, no be paara oh Control, no be galala To make money, no be by dragger Oh-oh-oh, aya-ya Heys, ọmọ tó bá ta féle-féle, ẹ gbá ojú ẹ Ẹ le pa (ẹ le pa), ó le kwà (ó le kwà) (anya o) Ọmọ tó bá bẹ sí mi, éè ní fara ire lọ, àh Ajurawalọ, ti ìjàkadì kọ, ìwọ náà mọ
Writer(s): Barry Jhay Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out