Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Rybeena
Rybeena
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adewale Oluwaseun Atanda
Adewale Oluwaseun Atanda
Songwriter
Oyeniyi Ademola Oluwatobi
Oyeniyi Ademola Oluwatobi
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Tobisneh
Tobisneh
Producer
Dopestiks
Dopestiks
Mixing Engineer

Lyrics

[Intro]
Tobisneh records
It’s Dopestiks baby
[Verse 1]
I’m in Las Vegas to pick
I don wait Chinese
A ṣi le muti ka fa loud
Duro de mi ni roundabout
Hop in my Chevrolet Camaro
They don ship my cargo
At'ẹni to fẹ ṣe crypto
Ni k'Ọlọhun ma jẹ a ṣagbako
Ki l'ọn sọ, sọ, sọ, sọ, sọ, sọ
I just wan hear money don drop, drop, drop, drop drop, drop
Bournvita licking Tom Tom, Tom Tom, Tom, tọhọhọ, huun
Omo t'ọn sọ, sọ, sọ
Ki l'ọn sọ t'ọn sọtan
[Bridge]
Wayo Allah
Aboki send the dollar (Send the dollar)
Ma jẹ a ralakoba adaba send the wire (Wey the wire)
[Bridge]
Wayo Allah
Aboki send the dollar (Send the dollar)
Ma jẹ a ralakoba adaba send the wire (Wey the wire)
[Verse 2]
Ma a jaye mi life is short, short
To ba ku wọn a pa ẹ ti, truth is bitter jẹ ki n sọ, sọ
Adewale Anabi lokeloke gbera tan
Ọmọ ologo from trenches drip on Louis wear Tomford
Ọmọ ọpẹ no fugazzi
[Verse 3]
Alimọtu, idi to ru
Idi to ru gba, gba ko jẹ ko mọ-ọnjo
Alimọtu, idi to ru
Idi to ru gba, gba ko jẹ ko mọ-ọnjo
[Bridge]
Wayo Allah
Aboki send the dollar (Send the dollar)
Ma jẹ a ralakoba adaba send the wire (Wey the wire)
[Bridge]
Wayo Allah
Aboki send the dollar (Send the dollar)
Ma jẹ a ralakoba adaba send the wire (Wey the wire)
[Verse 4]
Padi ẹ wo
Ṣo le gba idea lo?
Ṣọra fun ọmọ to ni bantẹ obo
To ṣe ma jẹ wo
O le ko si ko bẹ wo
Eh oh ai
Ani to ba ti n le ko wọn mi si diẹ wo
Diẹ ooh ooh
[Outro]
It’s Dopestiks baby
Written by: Adewale Oluwaseun Atanda, Oyeniyi Ademola Oluwatobi
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...