album cover
Oro Idile
522
World
Oro Idile was released on March 17, 2024 by Hondread as a part of the album Ifamurewa
album cover
Release DateMarch 17, 2024
LabelHondread
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM89

Credits

PERFORMING ARTISTS
Hondread
Hondread
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Damilola Makinde
Damilola Makinde
Composer, Lyrics
PRODUCTION & ENGINEERING
Damilola Makinde
Damilola Makinde
Producer
Projessi
Projessi
Mixing Engineer

Lyrics

(Hondread)
Ino nla ni ifa je
E je ka karajo ka di ifa mu
Adi fun won lode aja laye
Nibi ti won gbe ko isin ope sile
Ti won ni awon oni gbo ti ifa mo
Nje alado e wi ao sin
Isese awa la wa o sin
Isese
Kini isese ton se ni le yin oo
O je lo ja ara re
Ko ma bawon se
Kini oro idile yin o
Ja ra re
Ko lo ba won se
Omo onile o ma ranti ile mo
Many things wey we don troway
Nitori isin omo ba o ronu
Emi ti mo ti ja ra mi
Won paro fun awon baba nla wa
Won ko gogbo nkan ini wa
Won sope awn irunmole wa o da
Sugbon awon ni won wa ka
Ni won wa ko lo
Aje them still dey jonze us
O lo ka tabatiada
To ye ko ma da ifa
Inu o ye ko jeun
O lon fi ebi kpa
Obatala oba takun takun
Sango esu ogun oya osun
E wo lon se ni ile
Kini isese ton se ni le yin oo
O je lo ja ara re
Ko ma bawon se
Kini oro idile yin o
Ja ra re
Ko ma bawon se
Eni to gbagbe ile
So apo e ya ko
Te n ti e ni
Takisa ni ta tan
O ba pada si le
Ani ti ija ko
E ja lo bo egun
Mo si e ni gbere ipako
Forsake not your ancestor
Embrace your own culture
And dont you forget
Omo eni ti iwo nse
Pada sile pade sile
Find yourself
Pada sile pade sile
Find yourself
Kini isese ton se ni le yin oo
O je lo ja ara re
Ko ma bawon se
Kini oro idile yin o
Ja ra re
Ko ma bawon se
Written by: Damilola Makinde
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...