Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
9ice
9ice
Performer
Alexander Abolore Adegbola Akande
Alexander Abolore Adegbola Akande
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Alexander Abolore Adegbola Akande
Alexander Abolore Adegbola Akande
Composer

Lyrics

[Verse 1]
Nìkan mo dá ṣiṣẹ́ mi, 'jọ ma náwó mi
Nìkan ṣiṣẹ́ mi but a jọ ma náwó mi ni
Ọ̀tá mi má a tẹ́ ni 'cause èmi kọ́ mo sọ̀rọ̀
O jẹ́ bẹ́sẹ̀ rẹ sọ̀rọ̀ tí bájínátù bá ń sọ̀rọ̀
Ọ̀tá l'Ágerige l'Abbatior wọ́n ferége
I say t'ówó mi bá ń sọ̀rọ̀
O jẹ́ lọ kọ̀rọ̀, ah
[PreChorus]
Mo wọ Balenciaga (Aga)
And I gat the ego (Ego)
I grad it to proper (Walahi)
Debit ò lè kóbá mi
Sapá no dey do me anything
Mo wọ Balenciaga (Aga)
And I gat the ego (Ego)
I grad it to proper (Walahi)
Debit ò lè kóbá mi
Sapá no dey do me anything
[Chorus]
La la kú la
Èmi ti yàyàkúyà
Wá jẹ dòdò Ìkirè
Wá sọ vanacular
La la kú la
Èmi ti yàyàkúyà
Wá jẹ dòdò Ìkirè
Wá sọ vanacular
[Verse 2]
Hennessy amama, Òfílìgangà
Ẹ wò'dí Alhaja Robo
No be say wọ́n sọ mo rí ẹ l'Ájàó pé
Ooh ooh ooh, èní ma dùn
Kì í ṣọmọ kọ́mọ, common, jẹ́ kí n gbé ẹ dé'bẹ̀ o
[PreChorus]
Mo wọ Balenciaga (Aga)
And I gat the ego (Ego)
I grad it to proper (Walahi)
Debit ò lè kóbá mi
Sapá no dey do me anything
Mo wọ Balenciaga (Aga)
And I gat the ego (Ego)
I grad it to proper (Walahi)
Debit ò lè kóbá mi
Sapá no dey do me anything
[Chorus]
La la kú la
Èmi ti yàyàkúyà
Wá jẹ dòdò Ìkirè
Wá sọ vanacular
La la kú la
Èmi ti yàyàkúyà
Wá jẹ dòdò Ìkirè
Wá sọ vanacular
[Outro]
Aga
Ego
Aga
Òfílìgangà (Ego)
Ẹ wò’dí Alhaja Robo
No be say wọ́n sọ
Sapá no dey do me anything
Written by: Alexander Abolore Adegbola Akande
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...