Lyrics

Eni timofe denu adun aye mi ni Eni timo fo fun timo gbafun ife mi ni Ololufe mi timo yan gege bi ishan ara Timo ba nbinu, timo ba nbinu Timo ba nbinu tonbemi tinba sope rara Eyin e kanlo bami wa ololufemi lo Okan toti gbona atutu lalai b'omi si Iwo nimofe pe koma se'toju mi ni Modupe p'awon obi e gba, won o sope rara Bose nsemi gan mio leso, Olohun shaloye Ololufemi afiwo naa lotunye Bi adanwo ni oro ife toladun bi oyin, t'aba ti renikeji tonfeni denu Jerryson production Moyan ifemi nibi totida Mio kabamo pemose l'aya Olohun loni kinpe e lojoyen o, modupe Olohun motun t'opeda Moyan ifemi nibi totida Mio kabamo pemose l'aya Olohun loni kinpe e lojoyen o, modupe Olohun motun t'opeda MashaAllah Moyan ifemi nibi to tidun o Mio kabamo pemose loko Olohun loni kingba lati fe e o, modupe Olohun motun t'opeda Moyan ifemi nibi to tidun o Mio kabamo pemose loko Olohun loni kingba lati fe e o, modupe Olohun motun topeda Miio shife mo r'olooto momu Mio shiyan mo fenikeji s'aya Mo nigbagbo pewo sha layan funmi o, kajo mawa ni dojo ale ayami Moyan ifemi nibi totida Mio kabamo pemose l'aya Olohun loni kinpe e lojoyen o, modupe Olohun motun t'opeda Mio f'àlè soko mo r'olooto fisoko Mio siyemeji kinto ba e lo mogba Pewo gangan leni ti a yan momi o, taojo gbepo dojo ale okomi Moyan ifemi nibi to tidun o Mio kabamo pemose loko Olohun loni kingba lati fe e o, modupe Olohun motun t'opeda Oni o mani kolofin ojo ayo ni, igbeyawo alarinrin lawase loni o T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe Oni o mani kolofin ojo ayo ni, igbeyawo alarinrin lawase loni o T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe Sebi nigba ti e rirayin sebi enikan soso Lokoko so fenikeji pe jekadi ife ara? Iyawo lokoko sako oloun o gba o Oko e oje ko sinmi otun gbiyanju o Pomo totutu niwa lojo, sowa gbodo loni? Yoruba ni koje ngbadun lobinrin ngbafun Oun gangan niyawo e fiwa pada gba o Toko tiyawo alarede ti d'oloruka o E jeka fayo bawon dupe Oni o mani kolofin ojo ayo ni Igbeyawo alarinrin lawase loni o T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe Oko iyawo tiso funmi o l'oriyomi o Monife iyawo mi denu o koja wasa o O l'egbin nimo lefiwe boje t'ewa ni O l'adàbà lale fiwe boje t'iwa ni O lodabi oju lara tio gbodo fo O lodabi aso lara tio gbodo ya ni O loun maloje koun mo adun ife o Loje koun fi sepinnu poun gbodo fe Ni tako tabo alarede ba doloruka o Toko tiyawo alarede ti d'oloruka adupe Oni o mani kolofin ojo ayo ni Igbeyawo alarinrin lawase loni o T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe Iyawo matiso boseri lara oun gangan Iyawo matiso boseri lara oun O loko timofe wumi modupe oni o O leni bi okan mi o koja okunrin Tenikan leri ta gboju wipoun o ri Ajanaku koja kokoja ka laomo Iduro e ni kaso ni abi t'ewa ni Abi t'iwa t'okunrin fi nsike aya O loun gan time ipinnnu poun gbodo fe T'oko tiyawo alarede ba doloruka o, eje kafayo bawon mujo Oni o mani kolofin ojo ayo ni Igbeyawo alarinrin lawase loni o T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe MashaAllah Olohun ti soyin papo kema pada ja Olohun to seyin lokan niko fadunsi Oba toseyin lolufe emi ikorira Koni gbajoba ife yin allahumma amin Koni koro titi laye ife adun bi oyin ni K'ifedayo ke dolope keyin masepada dota Oni o mani kolofin ojo ayo ni Igbeyawo alarinrin lawase loni o T'oko t'iyawo alarede ti d'oloruka adupe Yah robbi maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai Maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai Yah robbi maje kiwon tuka o Allah Maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin ma delesinrin amin Maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai Yah robbi maje kiwon suffer o Allah Mase fiya dan won wo lailai Ilahi ma yawon lagan amin o K'esu masiwon lona Allah Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin ma doniranu amin Maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai Iyawo ojo oni o Allah Iyawo ojo oni o Allah Maje koso foko e po tan Ibagbe ibasepo ola Maje ko diso'nu eku Allah Amumora toba lefa ironu o Maje kiyen osele Amin Biwon sewa bere aye tuntun o ife K'igbeyawo alarinrin ma doniranu titi lai Maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai Olohun, agbara toko o malo fise Agbara toko yio malo fise Olohun mafi won oko e amin Maje kogba alagbase oru Oro toko o malo ba fun Maje k'oko o d'otubante o Ola tio fi kebi e ba nfun Biwon sefe bere aye tuntun tuntun o ife Igbeyawo alarinrin ma delesinrin, koma doniranu lailai Maje kiwon tuka o Allah Toko tiyawo oloruka ti dikanna o Biwon sewa bere aye tuntun o ife Igbeyawo alarinrin maje kodija lailai Alubarika ibe mafi dunwa karowo na Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o Omo abiro abiye tako tabo Alubarika ibe mafi dunwa karowo na Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o Omo abiro abiye tako tabo Terin tayo lafi pade ta finyo Isoro ibe mafi kanwa kama sunkun o Ka bawon gbe'beji abiro takotabo Alubarika ibe mafi dunwa karowo na Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o Omo abiro abiye tako tabo Ki toko taya mapada gbera sepe Ife tobere ni konmalo dojo ale won Irepo lafe kosele titi lai Alubarika ibe mafi dunwa karowo na Ebun ibe mafi dunwa karomo bi o, omo abiro abiye tako tabo Iyawo ti roko gbamu o adupe o O l'abelejayan kewabi joko si Oko ti riyawo e dimu o adupe o O l'abelejayan kewabi joko si Gbogbo Eni towa akiyin emama seun Ao firu e gba pelode idunnu Baba oko nkinyin pema mase o Ao firu e gba pelode idunnu Mama oko nkiyin pema mase ee Ao firu e gba pelode idunnu
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out