Credits
PERFORMING ARTISTS
Pappy Mufasa
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adebayo Yunis Damilare
Songwriter
Basit Hamzat
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Wiikedest
Producer
Lyrics
Emi Mufasa
Nínú aparte o, a n'jaye o (jaye o, jaye o)
Pẹlú àwọn shawry o, a n'parry o (parry o, parry o)
Wọ́n gbọ'mọ fún mi, mo ń mú ọtí o (mú ọtí o, mú ọtí o)
Oh na, but I miss you my shawry (shawry, shawry)
Call you my chargie (chargie, chargie)
Hmm, ninu aparte o, a n'jaye o (jaye o, jaye o)
Pẹlú àwọn shawry o, a n'parry o (parry o, parry o)
Wọ́n gbọmọ fún mi, mo mú ọtí o
(Mo mú ọtí o, mú ọtí o, mú ọtí o) (mo jaye ó)
But I miss you my shawry (shawry, shawry)
Call you my chargie (chargie, chargie)
Nínú aparte o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Nínú aparte o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Nínú aparte o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Nínú aparte o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Ìwọ sha má mín bayi (sha má mí bayi)
Ikebe yí ju ti Mumbai (bombe)
Mú inú mi dùn bayii (dùn bayii)
Tẹlé mi lọ kalọ Dubai (jẹ kalọ Dubai)
My shawry, mo ti mọ pe ẹnu ose (ose o)
My babe, fí wọ́n lẹ kan má pòsé (kan má pòsé o)
I dey with you my chargie (chargie) (hnn-hun-hun)
But me dey for Ghana (hun-hun-hun)
I come to jayé Kumasi (hun-hun-hun)
I dey with my padi Ogwuche, Musa string (hun-hun-hun)
Ye, tí ń bá ti mú wèrè yo
After party pẹlu awọn bororo (hun-hun-hun)
Ma lẹ ìgò mo ju mí ní o (hun-hun-hun)
As pé Ghana Girl dey sabi yoko-toto
Nínú aparte o, a n'jaye o (jaye o, jaye o)
Pẹ'lú àwọn shawry o, a n'parry o (parry o, parry o)
Wọ́n gbọ'mọ fún mi, mo mú ọtí o
(Mo mú ọtí o, mú ọtí o, mú ọtí o)
Oh na, but I miss you my shawry (shawry, shawry)
Call you my chargie (chargie, chargie)
Nínú aparte o, a n'jaye o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
(Jaye o, jaye o) (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Pẹlú àwọn shawry o, a n'parry o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
(Parry o, parry o) (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Wọ́n gbọmọ fún mi, mo ń mú ọtí o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
(Mú ọtí o, mú ọtí o, mú ọtí o) (uh-uh, ei-yei, uh-uh, ei-ye)
Oh na, but I miss you my shawry (shawry, shawry)
(Ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Call you my chargie (chargie, chargie) (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)
Nínú aparte o (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy) (ooh-h ay-ayy, ooh-h ay-ayy)

Nínú aparte o
Nínú aparte o, nínú aparte o
Nínú aparte o, nínú aparte o
Written by: Adebayo Yunis Damilare, Basit Hamzat