Lyrics

Ilu le o ko s'owo lode Ilu le o ko s'owo lode Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo Abi beeko Ani se e Bi sisi mura gege won a ka e mole, ani Bi sisi mura gege won a ka e mole Mo beere e titi won o jise fun e ni, Ani se e Iro lo n pa o owo lo n wa yen Mo beere e titi won o jise fun e ni, anio Iro lo n pa o naira lo n wa yen Ilu le o ko s'owo lode Ilu le o ko s'owo lode Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo Obinrin n kigbe okunrin n kigbe kaluku lo n kegbe owo Bi sisi mura gege won a ka e mole Bi sisi mura gege won a ka e mole Mo beere e titi won o jise fun e ni Iro lo n pa o owo lo n wa yen Mo beere e titi won o jise fun e ni Iro lo n pa o naira lo n wa yen
Writer(s): L Baja Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out