Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Ajulo Jesu
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adetunji Ajulo
Songwriter
Lyrics
Call: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba,
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo Gbo osoba fun o kare,(2x)
Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o),
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo gbo osoba fun o kare, (2x)
Verse
Emi dupe ore pe apa aye o kami,
Emi dupe ore pe o dami si,
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo de gbo osoba fun o kare, (2x)
Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o),
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo gbo osoba fun o kare, (2x)
Ye, Oni duro gbogbo wa,
Alanu eda Oloore mi to gbo jije mimu,
Iwo la shore fun ma si re gun o,
Mo gbo osoba fun o kare, (2x)
Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o),
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo gbo osoba fun o kare, (2x)
Call: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba,
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo Gbo osoba fun o kare,(2x)
Res: Oba tin sore fun ni lai wo be,
Mo wa yin o baba (mo wa yin o o),
Iwo lo n shore fun e ni ti o mo yi,
Mo gbo osoba fun o kare, (6x)
Written by: Adetunji Ajulo