Credits

COMPOSITION & LYRICS
Gideon Olasunkanmi Adeola
Gideon Olasunkanmi Adeola
Songwriter

Lyrics

Alalani ogo
Right here through the storm's fury.
As the heavy blue wind blew through.
And the voice whispers to me.
With the rising sun.
His promises unfold.
Like petals unfurling to greet the dawn.
My heart finds solace, in his promises unfold.
Now I have found, the greatest of love, and his protection, forever and ever.
HOOK
Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo,
Oba Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo.
Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo.
Oba Oluwa nbe leyin mi.
CHANT
Eri oooolola Alagbara giga Oba Iyanu mosebare.
Agbada Eru nlo wo, ade aiyeraiye nlode.
Iji to ju iji lo to gbe iji mi ola nla ninu afefe oo.
Yagwaigaladala madazairu, Eeelishadahi.
Oluwa awon omo ogun taye nsaa to nigba togun aye bade.
Pere bi ewe bo.
Omowa kia to mo.
Otigbo kaato mawi otimo kia to maa soro.
Uun ara waa wo waa Iwo nla nwaa ka.
Emi o mo Oba toun foba je to tun le ro oba bi ose iwo olorun to tin joba ki gbogbo aiye to fi oba ti won je o.
Iwoooooo laoma bo oooooo.
HOOK
Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo,
Oba Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo.
Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo.
Oba Oluwa nbe leyin mi.
Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo,
Oba Oluwa nbeeeeeeee.
Oluwa nbe leyin mi, eru ko si fun mi mo.
Oba Oluwa nbe leyin mi.
17 BARS SAX SOLO INTERLUDE
Oluwa nbeeeeee ee (5 times)/Horns arrangement
Lord of mercy.
Uuuuuuu.
Lord of mercy.
Written by: Gideon Olasunkanmi Adeola
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...