Credits

PERFORMING ARTISTS
Adekunle Gold
Adekunle Gold
Performer
COMPOSITION & LYRICS
King Sunny Ade
King Sunny Ade
Songwriter
Adekunle Kosoko
Adekunle Kosoko
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Mela
Mela
Producer
Seyifunmi Michael
Seyifunmi Michael
Producer
David Donnelly
David Donnelly
Mastering Engineer

Lyrics

[Intro]
Baba ti gbọ, Baba ti gba
Ire gbogbo baba ṣe fun mi
[Verse 1]
Ijo n bẹ lẹsẹ mi o
O ya bọta ko wa jo
Ẹ jẹ ka yin Eledumare o
Ha! Iyin lo tọ si Eledumare Ọba mimọ
Me le ṣe lai ma yin Eledumare
Mo wa wọ bata ijo mo fẹ jo f'Oluwa
[Chorus]
Me le ṣe o
Me le ṣe
Me le ṣe o k'emi ma ṣai yin Baba logo
Me ma le ṣe k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me le ṣe k'emi ma ṣai jijo ọpẹ o
Me le ṣe
Me le ṣe o k'emi ma ṣai yin Baba logo
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
[Verse 2]
Tori onigba n gbegba
Alawo n gbawo
Emi n gbe igba ọpẹ s'Oluwa Allahu Rabbi
Alatilẹyin ọba ti ki i doju tini
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Ijo alayọ re o maa jo
[Chorus]
Me ma le ṣe k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me le ṣe o k'emi ma ṣai yin Baba logo
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me le ṣe, me le ṣe, me le ṣe ṣe o
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Onibuọrẹ, Agbanilagbatan mo tun de
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me ma le ṣe ṣe k'emi ma ṣai yin Baba logo
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
[Verse 3]
Tori onigba n gbegba
Alawo n gbawo
Emi n gbe igba ọpẹ s'Oluwa Allahu Rabbi
Alatilẹyin oba ti ki i i doju tini
[Chorus]
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me le ṣe o k'emi ma ṣai yin Baba logo
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me le ṣe, me le ṣe, me le ṣe ṣe o
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Onibuọrẹ, Agbanilagbatan mo tun de
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Me ma le ṣe ṣe k'emi ma ṣai yin Baba logo
Me ma le ṣe o k'emi ma ṣai jijo ọpẹ
Written by: Adekunle Kosoko, King Sunny Ade
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...