album cover
Easy Sixtem
1
Music
Easy Sixtem was released on March 12, 2025 by SIXTEMLOMONA as a part of the album Fuji Sixtem - EP
album cover
Release DateMarch 12, 2025
LabelSIXTEMLOMONA
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM96

Credits

PERFORMING ARTISTS
Sixtem
Sixtem
Performer
Lasisi Akeem Sanni
Lasisi Akeem Sanni
Keyboards
COMPOSITION & LYRICS
Lasisi Akeem Sanni
Lasisi Akeem Sanni
Songwriter
Johnson Ayodele
Johnson Ayodele
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Johnson Ayodele
Johnson Ayodele
Mixing Engineer, Mastering Engineer, Producer

Lyrics

Ahn Ahn
Ahn Ahn
Kò ní le f’ọ́lẹ kó má le j’ẹ̀bà o
Iṣẹ́ di ṣíṣe bàbá má jẹ́ n jẹ́’ka
Lọ́lá satiramoni má jẹ n jábọ́ má jẹ́ n ṣubú
Ah ah Sixtem, orin tuntun pẹ̀lú ìlù tuntun
Back in the days t’a bá ń ṣ’eré Fújì wọ́n á pè wá lọmọ ìta
Omi tuntun ti rú
Ẹja tuntun wọ inú odò o
Sixtem lọmọ náà
(Ah easy sixtem)
À ti lọ s’óde ọ̀fẹ́ rí (Ah easy sixtem)
A ti bẹ̀bẹ̀ ká wá ṣ’eré rí (Ah easy sixtem)
Mélòó la fẹ́ kà mélòó la fẹ́ rò o (Ah easy sixtem)
Ṣé t’elégbè mi àbí t’onílù mi ni (ah easy sixtem)
Mi ò le gbàgbé ọjọ́ náà ní Mushin (Ah easy sixtem)
Ó ti d’ọ̀rọ̀ ìtàn ìyẹn mà ti bá àná lọ o (Ah easy sixtem)
Mo ti gbé tuntun dé, gbé tuntun dé dé dé (Ah easy sixtem)
Ká jọ mùkulu, ká jọ mù kẹkẹ
Kò lè yé wọn b’ómi ṣe gbà wọnú àgbọn
Kò lè yé wọn bí mo ṣe ń jẹun lọ
Kàyéfì ló jẹ́ fún wọn bí mo ṣe ń jẹun ayọ̀ mi
(Jẹun ayọ̀ mi o)
Ọ̀tá fẹ́ yọ̀ kí ṣùgbọ́n àwọn kọ́ ló dá mi (Wọ́n ti gbàgbé ni)
Omi tuntun ti rú ẹja tuntun ti wọnú odò
 
Eh! Sixtem lọmọ náà (Ah easy sixtem)
À ti lọ s’óde ọ̀fẹ́ rí (Ah easy sixtem)
A ti bẹ̀bẹ̀ ká wá ṣ’eré rí (Ah easy sixtem)
Mélòó la fẹ́ kà mélòó la fẹ́ rò o (Ah easy sixtem)
Ṣé t’elégbè mi àbí t’onílù mi ni (ah easy sixtem)
Mi ò le gbàgbé ọjọ́ náà ní Mushin (Ah easy sixtem)
Ó ti d’ọ̀rọ̀ ìtàn ìyẹn mà ti bá àná lọ o (Ah easy sixtem)
Mo ti gbé tuntun dé, gbé tuntun dé dé dé (Ah easy sixtem)
Ká jọ mùkulu, ká jọ mù kẹkẹ
Àdáṣe ní ń hun’mọ
Ìbà ò gbudọ̀ hun’mọ
Àdáṣe ní ń hun’mọ
Ìbà ò gbudọ̀ hun’mọ
Mo ṣè’bà fún àwọn tí wọ́n ń bẹ níwájú
Kí n lè jẹun pẹ́ pẹ́ pẹ́
Kí n le fèrìgì jobì o
Sixtem (Ah easy sixtem)
À ti lọ s’óde ọ̀fẹ́ rí (Ah easy sixtem)
A ti bẹ̀bẹ̀ ká wá ṣ’eré rí (Ah easy sixtem)
Mélòó la fẹ́ kà mélòó la fẹ́ rò o (Ah easy sixtem)
Ṣé t’elégbè mi àbí t’onílù mi ni (ah easy sixtem)
Mi ò le gbàgbé ọjọ́ náà ní Mushin (Ah easy sixtem)
Ó ti d’ọ̀rọ̀ ìtàn ìyẹn mà ti bá àná lọ o (Ah easy sixtem)
Mo ti gbé tuntun dé, gbé tuntun dé dé dé (Ah easy sixtem)
Yeah omi tuntun ti rú
Ẹja tuntun ti kó wọ’dò
Èmi omi yín náà ni o Sixtem
Written by: Johnson Ayodele, Lasisi Akeem Sanni
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...