Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Islambo
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Oluwaseun Opeyemi Olajuwon
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
SKUCHIES MIX
Mastering Engineer
Niphkeys
Producer
Lyrics
Ha, hold something
(Niphkeys)
Oba aláṣàkaṣà
The street is highly congested
Àwa ma ri nkàn jẹ sẹ
Wobey and tested
Akínkanjú no be Ben 10
Wells Fargo yàtọ sí Kuda
Bi Hennessy ṣe yato si Gulder
Steady carrying ewé, I'm not carried away
Hold something
Consolidate
Eni ṣíṣe lon ṣo holiday
Consoli-gbadun
Akata lan basun
Consoli-japon
Malo gbe iyabo ni Jákàndé
Consolidate (Haibo)
At the same time kos'holiday
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (Wa gbọ lamba yi)
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (Jọ wa gbọ lamba yi)
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (Abi ẹ gbọ lamba ni?)
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude
My lamba is surplus
Ẹ ma jasi, ẹ wa gbasi
I'm active like thief
Koto di pe won laju pa (Koto di pe won laju pa)
O tidi baraku bai (O tidi baraku bai)
Igbadun o si feni to ja
Tan t'Ọlọ́run ke hallelujah
Ha, òdòdó lọ'wọ', igbàyílolá
Lamba ti o sin Google (Lamba ti o si n Google)
Jọ wo synagogue (Jọ wọ synagogue)
Abi ẹ nri double (Ha, ya, ya)
Kọlu ni o ni cuddle
Consolidate
Eni ṣíṣe lon ṣọ holiday
Consoli-gbadun
Akata lan basun
Consoli-japon
Malo gbe Iyabọ ni Jákàndé
Consolidate (haibo)
At the same time ko s'holiday
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (Wa gbọ lamba yi)
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (Jo wa gbọ lamba yi)
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (Abi ẹ gbọ lamba ni?)
Let him cook (Ṣe e ngbọ lamba yi?)
Hear this dude (E wa gbọ lamba)
Talo lo panadol?
Jo mama dull
Ha, lamba po
Jọ, jọ, jọ
Written by: Oluwaseun Opeyemi Olajuwon

