Credits
PERFORMING ARTISTS
Spirit of Prophecy
Background Vocals
Adejola Rhapsody Dosunmu
Rap
COMPOSITION & LYRICS
Adejola Rhapsody Dosunmu
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Adebola Shammah
Producer
Adebola Shammah Olaniran
Producer
Lyrics
[Verse 1]
To ba gbọ pe ide mi ja o yẹ ko ti mọ pe ṣẹkẹṣẹkẹ ti bọ
To ba gbọ pe ide mi ja o yẹ ko ti mọ pe ṣẹkẹṣẹkẹ ti bọ
Oluwa loluṣọ agutan mi ohun Oluwa naa dẹ ni mo n gbọ
Ọrọ Oluwa iye ni o ya la eti rẹ ko wa jẹ ko wọle
Ọrọ ti o mu ọmọ to ti sọnu to mu ọmọ yẹn pade rele
Faith is my currency o ya ka Bible ẹ ko ko fi cash out (Ko fi cash out)
His mercies are new every morning o ya subscribe ko to step out (Ko to step out)
Nigba ti ebi n pa mi Jesu ni bread of Life
Jesu ji oku dide Jesu eternal life
Jesu fun mi ni alaafia laisi ni Nasarawa
Isinmi wa ninu Jesu ọmọ ọpẹ o ya sare wa
Goodness and mercies dey follow
From now until tomorrow
And everything wey I get ọmọ na my own me I no borrow
[Verse 2]
Ninu aye, Jesu yọ mi kuro ninu aye
O ra mi pada o wa sọ mi dọmọ mo wa dupẹ lọwọ ayeraye (Ayeraye)
Ninu aye, Jesu yọ mi kuro ninu aye
O ra mi pada o wa sọ mi dọmọ mo wa dupẹ lọwọ ayeraye
[Chorus]
O fun mi ni
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
[Verse 3]
His Goodness and mercies is uncountable
Anytime wey call o wa available
In the presence of enemy You prepare a table
O dẹ jẹ ki n wa comfortable
Ogo, Ogo
O ya gba gbogbo ogo ogo
Iwọ lo yẹ lati gba gbogbo ọla, agbara, imọ ati gbogbo ogo
Judah, Judah
Lion of the tribe of Judah
Awọn agbaagba mẹrinlelogun wolẹ niwaju rẹ wọn wa juba (Wọn wa juba)
Judah, Judah
Lion of the tribe of Judah
Awọn agbaagba mẹrinlelogun wolẹ niwaju rẹ wọn wa juba
[Verse 4]
Aribirabata (Aribirabata)
Arabaribiti (Arabaribiti)
Iṣẹ ti baba n ṣe kabiti kabiti (Kabiti kabiti)
Tani, tani, tani, tani emi ma tẹle? (Jesu)
Tani, tani, tani, tani emi gbẹkẹle?
[Chorus]
O fun mi ni
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
O fun mi ni
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Igbala, iwosan, ilera pipe
Written by: Adejola Rhapsody Dosunmu