album cover
Shoki
album cover
Shoki was released on June 4, 2014 by RUN as a part of the album Shoki - Single
June 4, 2014
LabelRUN
LanguageEnglish
BPM136
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Lyrics

Ha, ha
Ha, ha
Ha, ha
Ha, ha
Oya, shoki kì ń shoki, ha
Bá mi wá ọmọgẹ́ tó bá yọ̀ dí, ha
Mi ò ní kó wá twerk tó wà gbọ́n dí, ha
All I want her to do is to shoki, shoki kì ń shoki
Shoki kì ń shoki, ha
Bá mi wá ọmọgẹ́ tó bá yọ̀ dí, ha
Mi ò ní kó wá twerk tó wà gbọ́n dí, ha
All I want her to do is to shoki, shoki kì ń shoki
Ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki (All I want her to do is to shoki)
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki (All I want her to do is to shoki), shoki
Wọ́n lè wo, mo gbé dé yìí, ha
Ẹ jọ̀ọ́, ijó shoki lẹ́ lẹ́yìí, ha
Ẹ jọ̀ọ́, ijó ìgboro lẹ́ lẹ́yìí, ha
Anyway, àwọn butty lẹ́jó sí, no problem
Nọwọ́ síwájú
K'ejìká máa lọ sọ̀tún sọ́sì
Má fò sókè díẹ̀ díẹ̀
Ó ṣe, ọ̀yá f'ákọ̀ sí, ọ̀yá f'ákọ̀ sí
Ọ̀yá shoki, kí n shoki (Ha)
In the club, anything we are popping (Ha)
Ẹ bá mi w'ọmọ tó sexy o jàre (Ha)
Kó wá jó shoki fún mi o jàre, no problem
Shoki, kí n shoki (Ha)
In the club, anything we are popping (Ha)
Ẹ bá mi w'ọmọ tó sexy o jàre (Ha)
Kó wá jó shoki fún mi o jàre, eh, o jàre, ah
Oya, shoki kì ń shoki, ha
Bá mi wá ọmọgẹ́ tó bá yọ̀ dí, ha
Mi ò ní kó wá twerk tó wà gbọ́n dí, ha
All I want her to do is to shoki, shoki kì ń shoki
Shoki kì ń shoki, ha
Bá mi wá ọmọgẹ́ tó bá yọ̀ dí, ha
Mi ò ní kó wá twerk tó wà gbọ́n dí, ha
All I want her to do is to shoki, shoki kì ń shoki
Ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki (All I want her to do is to shoki)
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki (All I want her to do is to shoki), shoki
Mummies to the daddies
To the fine boys to the sexys
If you're feeling this song-y
Come join me to shoki
If you get it, you are lucky
I will dash you my money
Stop dancing like a monkey
Let me teach you how to shoki
Óyá, nọwọ́ síwájú, ha
K'ejìká máa lọ sọ̀tún sọ́sì, ha
Má fò sókè díẹ̀ díẹ̀, ha
Ó ṣe, ọ̀yá f'ákọ̀ sí, ọ̀yá f'ákọ̀ sí
Nọwọ́ síwájú, ha
K'ejìká máa lọ sọ̀tún sọ́sì, ha
Má fò sókè díẹ̀ díẹ̀, ha
Ó ṣe, ọ̀yá f'ákọ̀ sí, ọ̀yá f'ákọ̀ sí, ah
Oya, shoki kì ń shoki, ha
Bá mi wá ọmọgẹ́ tó bá yọ̀ dí, ha
Mi ò ní kó wá twerk tó wà gbọ́n dí, ha
All I want her to do is to shoki, shoki kì ń shoki
Shoki kì ń shoki, ha
Bá mi wá ọmọgẹ́ tó bá yọ̀ dí, ha
Mi ò ní kó wá twerk tó wà gbọ́n dí, ha
All I want her to do is to shoki, shoki kì ń shoki
Ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki (All I want her to do is to shoki)
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki
Shoki, ha, shoki (All I want her to do is to shoki), shoki
Written by: Davido, Lil Kesh, Olamide

Loading...