Jafafa
36,971
Music
Jafafa was released on March 11, 2021 by Tiger music as a part of the album Jafafa - Single
Most PopularPast 7 Days
02:15 - 02:20
Jafafa was discovered most frequently at around 2 minutes and 15 seconds into the song during the past week
00:00
02:10
02:15
02:20
02:30
02:45
00:00
03:01
Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Chinko Ekun
Performer
MohBad
Performer
Zaki Amujei
Keyboards
COMPOSITION & LYRICS
OLADIPO OLAMIDE
Composer
Ilerioluwa Aloba
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Zaki Amujei
Producer
Lyrics
[Chorus]
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma jafafa
Aṣọ oju Lagbaja (Aṣọ oju Lagbaja)
Wọn ti lọ fi ran pata (Wọn ti lọ fi ran pata)
CD bọda Nuru (CD bọda Nuru)
Wọn ti fi gba guguru (Wọn ti fi gba guguru)
[Verse 1]
Ọmọ to ba jafafa
Ṣebi oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba bọ pata
Credit alert lo ma gbọ pan-pan (Gbọ pan-pan)
Awa lẹnu wa ti ja fa-fa
Ẹ wo lion to lọ n sa f'aja
Ẹ lọ jabọ sinu ṣalanga
Awọn alakọri lọ rojọ wa fun Lagbaja
Ọmọ to ba calm down lo ma gba bone straight
Ẹni fẹyin si wa lo ma gba Colgate
A kero wọnu club wọn tun kigbe no space
Awọn iya mi loru o ma ki n sanwo tollgate
[Bridge]
Wọn bẹ ẹ, o gbọ
Wọn bẹ ẹ, o gba
Wọn sa ẹ, o gbọ
Wọn sa ẹ, o ja
Number ẹ o lọ
O r'ọja o fa
Matter ẹ long, anaconda
[Chorus]
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma jafafa
Aṣọ oju Lagbaja (Aṣọ oju Lagbaja)
Wọn ti lọ fi ran pata (Wọn ti lọ fi ran pata)
CD bọda Nuru (CD bọda Nuru)
Wọn ti fi gba guguru (Wọn ti fi gba guguru)
[Verse 2]
CD bọda Nuru l'ọn fi ta suya fun wọn
Gucci perf l'ọn fẹ ra l'ọn fi ta lọfinda fun wọn
Ṣebi ẹ lẹ mad ni a o ni gba fun wọn
Awọn to wa iṣubu wa amin aṣẹ ko ni da fun wọn
Ẹ ma binu pe mo ṣepe
Hustling for pay day
Gbori wọnu lamba, sa fun ija bi okete
A ti mọ yẹn tey tey idi wa lẹyin na ege
Afunni ma wo'bẹ, ma screenshot, IBD Dende
[Bridge]
Wọn bẹ ẹ, o gbọ
Wọn sa ẹ, o gbọ
Number ẹ o lọ
O r'ọja o fa
Matter ẹ long, anaconda
[Chorus]
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ma jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ba jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Ọmọ to ma jafafa
Oun lo ma ṣa prapra
Aṣọ oju Lagbaja (Aṣọ oju Lagbaja)
Wọn ti lọ fi ran pata (Wọn ti lọ fi ran pata)
CD bọda Nuru (CD bọda Nuru)
Wọn ti fi gba guguru (Wọn ti fi gba guguru)
Written by: Ilerioluwa Aloba, OLADIPO OLAMIDE


![Watch Chinko Ekun ft Mohbad - Jafafa [ Official Audio ] on YouTube Watch Chinko Ekun ft Mohbad - Jafafa [ Official Audio ] on YouTube](https://i.ytimg.com/vi/BS7UkTH7c3U/maxresdefault.jpg)