album cover
Orisun
album cover
00:05
01:50
02:00
02:15
02:25
03:45
00:00
04:59
Past 7 Days
Orisun was discovered most frequently at around 2 minutes into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Intro]
Ati ọdọ rẹ lati ṣẹ wa o Eledumare
Oriṣa Apebọ, Oriṣa Apesin, Baba mi, Baba mi, Baba mi wura
[Chorus]
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
[Verse 1]
Bi ko ba ṣe ti, bi ko ba ṣe tirẹ
Aye i ba ti kẹru mi si igbo
Bi ko ba ṣe ti, bi ko ba ṣe tirẹ
Ọta i ba sọ mi dẹni ana o
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
[Verse 2]
Ah ah a fun mi l'anfaani nla
Lati fọn ipe na kikan seti ọmọ araye gbogbo
K'ọn le mọ pe iwọ ni aṣẹda mi
Iwọ l'alamọ ire to mọ mi're
To da mi pe, to da mi da
Ti o dẹ fi igba kankan da mi da, ko da mi da iṣoro mi
Omi to gbagbe orisun rẹ o ṣe tan lati gbẹ ni
Mi o jẹ gbagbe rẹ o Baba mi, ọkọ mi orisun mi
[Verse 3]
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Ẹni to mu wa lọwọ dani ninu irin ajo yii o
Abanija majẹbi ẹni iwọ ni
Paripari ọla paripari ogo
Abanidebe-ma-ma-da ni iwọ ni o
Ariraranjuranlọ iwọ ni ọkọ mi
Iwọ l'orisun mi eh oh
Iwọ l'orisun mi ati iye mi, Jesu
Ọba aiku, Ọba aisa, Ọba aidibajẹ o
Ọdọ rẹ lati ṣẹ wa o Eledumare (Ọdọ rẹ lati ṣẹ wa o)
Eleduwa wa (Eledu o mare o)
Eleduwa wa (Eledu o mare o)
Eleduwa wa (Arugbo, arumatẹjẹ)
Eleduwa wa (Orule ti n baja mọlẹ o)
Apanla to so ile-aye ro
Jesu
Oriṣa Apebọ, Oriṣa Apesin, Baba mi, Baba mi wura
[Chorus]
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Iwọ lorisun mi ati iye mi, Jesu
Written by: Paul Tomisin

Loading...