album cover
Edumare
103
Music
Edumare was released on October 17, 2025 by DAW EMPIRE as a part of the album ADISA
album cover
AlbumADISA
Release DateOctober 17, 2025
LabelDAW EMPIRE
LanguageEnglish
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM117

Credits

PERFORMING ARTISTS
Tolibian
Tolibian
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Abubakar Ottan Abdulmutolib
Abubakar Ottan Abdulmutolib
Lyrics
PRODUCTION & ENGINEERING
Kdream
Kdream
Producer

Lyrics

[Verse 1]
Alien
See as I dey work, see as I dey grind
See as I dey steady I dey bomb
See I dey buy risk e be must
Life Solomon Grundy you know
I need you, I miss you
I no still bend for one or two
Life e full gratitude but I choose you
[Chorus]
Ṣo mọ pe
Wọn ma gbayawo ọlẹ o
Ti o ba le tẹpa mọṣẹ o
Ọmọ ẹlẹ yii yọgbẹ wo
Iṣẹ aboki mujemu
Wọn ma gbayawo ọlẹ o
Ti o ba le tẹpa mọṣẹ o
Ọmọ ẹlẹ yii yọgbẹ wo
Iṣẹ aboki mujemu (Let's go, let's go)
Eledumare je a pẹ funra wa
Ki Baba loke je a pẹ funra wa (Amin o)
Eledumare je a pẹ funra wa
Ki Baba loke je a pẹ funra wa
[Bridge]
Tell me where you dey my love
Tell me where you dey my love
Omotena baby ma i lọ, why love
Omotena baby ma i lọ
Omotena baby ma i lọ
[Verse 2]
As you can see clearly ọmọ ju ọmọ lọ
As I dey here dey jollof
Ko dẹ sẹni to n demo
Wọn le ri iru mi
Mo ti trabaye mo ti jẹlọ
Awọn temi wọn stand gidigba
Mo ti gbẹyinkule wọnu wọn lọ
Wọn ba (Wọn ba)
[Chorus]
Ṣo mọ pe
Wọn ma gbayawo ọlẹ o
Ti o ba le tẹpa mọṣẹ o
Ọmọ ẹlẹ yii yọgbẹ wo
Iṣẹ aboki mujemu
Wọn ma gbayawo ọlẹ o
Ti o ba le tẹpa mọṣẹ o
Ọmọ ẹlẹ yii yọgbẹ wo
Iṣẹ aboki mujemu
Eledumare je a pẹ funra wa (Amin o)
Ki Baba loke je a pẹ funra wa
Eledumare je a pẹ funra wa
Ki Baba loke je a pẹ funra wa
[Outro]
Eledumare je a pẹ funra wa oh oh
Ki Baba loke je a pẹ funra wa
Eledumare je a pẹ funra wa
Ki Baba loke je a pẹ funra
Written by: Abubakar Ottan Abdulmutolib
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...