album cover
Eledami
album cover
Eledami was released on October 17, 2025 by DAW EMPIRE as a part of the album ADISA
AlbumADISA
October 17, 2025
LabelDAW EMPIRE
LanguageEnglish
BPM
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Lyrics

[Verse 1]
Ka bi ẹ o si o, ni Fadillulah
Where the light shines is where I go
In the night time walk a mile o
Make I no go see wetin go make me shout 'had I known!'
Everywhere I go dem dey call me aarẹ ọna kanfo
Nobody fit do me wayo
Iwọ to ba binu ko lọ ma jẹ kanfo
Ko le dabi t'Ọlọhun
I do appreciate your love
Mo appreciate
Ọlọrun ọba lo n ṣe ko dẹ ni ṣu lati gbe mi
To ba wa lori teblii, ọkan ọta mi o ni balẹ
Uhn uhn ehn
[Chorus]
Ẹlẹda mi o gbabọde mo dupẹ o ṣe
Ẹni fẹ mi f'ere o pọ, eyan Fadillulah
Emi ẹni ana dẹni taye damọ
Mo ni ka bi ẹ o si o, mo dupẹ o ṣe o
[Chorus]
Ẹlẹda mi o gbabọde mo dupẹ o ṣe
Ẹni fẹ mi f'ere o pọ, eyan Fadillulah
Emi ẹni ana dẹni taye damọ
Mo ni ka bi ẹ o si o, mo dupẹ o ṣe
[Chorus]
Ẹlẹda mi o gbabọde mo dupẹ o ṣe
Ẹni fẹ mi f'ere o pọ, eyan Fadillulah
Emi ẹni ana dẹni taye damọ
Mo ni ka bi ẹ o si o, mo dupẹ o ṣe
[Outro]
Mo dupẹ o ṣe
Awa n ṣọpẹ f'Ọlọrun
Mo wa dupẹ, mo wa dupẹ
Mo wa dupẹ f'Ọlọrun, un
Mo wa dupẹ, mo wa dupẹ ẹ
Written by: Abubakar Ottan Abdulmutolib
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...