album cover
Believe
album cover
Believe was released on May 8, 2026 by Young Preacher / FPR Ltd as a part of the album Close to Being a God
May 8, 2026
LabelYoung Preacher / FPR Ltd
LanguageEnglish
BPM54
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Music Video

Music Video

Lyrics

[Verse 1]
You don’t know the the things that we’ve been through
All the pains you feel, I feel too
Ṣo mọ nnkan toju ri ninu lungu?
Ko si choice lo jẹ n y'ọmọ buruku
Buh ẹ ma n blame mi
Good boy ti mo n ṣe yẹn o pay mi
So, mo choose pe ma rewrite fate mi
It’s crazy
Mo gbe, wo blood ninu face mi
[Verse 2]
You can’t be holy than Christ
I no wan see mama cry
Ata wa ko sowo rice
Ọkan kan la fi n ju dice
Ya ipanle ka le survive
E hard
[Verse 3]
Going on memory lane
All my life my papa no dey
Now papa don die not sure I’m okay
Alone mo gbori soke
Then I promise myself that I’m never gon fail
Mummy ma jẹun ọmọ
Daddy ẹ ma jẹun ọmọ
Though my dad is not here no more
Life's not fair, ṣo mọ?
Life’s not fair
[Verse 4]
Ka bi ọ o si Eleduwa
Iya yii pọ wo bo ṣe n wo wa
Ba wa pẹtu sọkan nibi to n dun wa
[Verse 5]
Jehovah come through for us
Come fight our battles for us
Your promise how come you forgot
Buh people told me to be strong
[Verse 6]
Ma worry o ṣi ma sup
Believe, ọkan kan pẹlu igbagbọ
Iwọ ṣa nigbagbọ
Ṣa nigbagbọ
[Chorus]
Ki i se l'ainireti
Ni mo tọ ọ wa
Ki i ṣe l'ainigbagbọ
Ni mo wolẹ
Ẹṣẹ ti gori mi
Eyi ṣa lẹbẹ mi, eyi ṣa lẹbẹ mi
Jesu ti ku
Ṣa nigbagbọ
Ẹṣẹ ti gori mi
Iwọ ṣa nigbagbọ
Eyi ṣa lẹbẹ mi
Ṣa nigbagbọ
Eyi ṣa lẹbẹ mi
Ẹjẹ ṣa nigbagbọ
Jesu ti ku
O ma set, believe
Ṣa nigbagbọ
Written by: Olalere David Joshua
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...