Lyrics

Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ o Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ o Mà jẹ ń kùnà, Bàbá, mú mí dé'lé o Mà jẹ ń kùnà, Bàbá sẹ, mú mí dé'lé o Owó tí mò ní, kò lé mù mí d'élé o Mọto tí mo rí rà, kò lé wá mi d'élé o Ọrẹ tí mò ní, kò lé sìn mí d'élé o Gbogbo ìwé tí mo rí kà, wọn gbé mí re'lé o Mà jẹ ń kùnà, Bàbá, mu mí dé'lé o Kiń mà kú sajo bíi èéfín, mu mí dé'lé o Aye l'ọjá, ọrùn nílé, mu mí dé'lé o Aye l'ọjá, ọrùn nílé sẹ, mu mí dé'lé o Mù mí dé'lé o (dé'lé) Mù mí dé'lé o (dé'lé, dé'lé) (Ilé) mù mí dé'lé o (dé'lé) Mù mí dé'lé o (dé'lé o) Mù mí dé'lé o (dé'lé) Mù mí dé'lé o (dé'lé, dé'lé) (Ilé) mù mí dé'lé o (dé'lé) Mù mí dé'lé o (dé'lé o) Mà-mà jẹ ń kùnà (ayọ, ayọ, ayọ o) Bàbá oo (Ayọ, ayọ, ayọ o) Bàbá o (Ayọ, ayọ, ilé ayọ) mu mí d'élé o Mù mí dé'lé o (ayọ, ayọ, ayọ o) Mù mí dé'lé o (ayọ, ayọ, ayọ o) Mù mí dé'lé o (ayọ, ayọ, ilé ayọ) Mù mí dé'lé o Ilé ògo, ilé ayọ Ilé ayọ, ilé àlàáfíà Ilé ògo, ilé ayọ Ilé ayọ, ilé àlàáfíà Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ Ìjọba ọrùn lérè onígbàgbọ́ o Mà jẹ kùnà
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out